O
This Odu highlights the importance of generosity and kindness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ofun bala difafun akanju oola
Adifafun akanju ola
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da fayi ki
Eleyi o rubo nuitori ola kosi
Ma kanju ifa ni ola re konipe
Tio fi de
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etuEyeleEko
Epo
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Aja nio wuko
Akuko adie ni oha Kelenbe gbe mi
Ita gba-n-gba gbangba
Ni solu ware ni pele
Adifafun edun oun iwa
Ti won jo nu rin lailai
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi
Ki eleyi orubo nitori aje
Ifa ni ore kan nbe fun
Eleyi ifa ni won o gbodo yara
Won rara nitori ire ola
Ifa pere fun enitoda fayi k elelyi orubo ifa ni elelyi
Fe ba eni kan toniagbarajai ka ni komo ba eni naa jao
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adieEyelePepeye
Eko
Epo
Opolopo owo
Igbin
Akuko adie
Eko
Epo
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ofun bala olobara bati
Adifafun Onibara
Omo ayeyere atiogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko
igbin
Eko
Epo
Opolopo owo
Agbebo adie
Eku
Eja
Eko
Epo
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ogbo imodo ni koyin seyin
Adifafun arefun we ti se
Aya agbon niregun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere omo fun eni tia
Da ifayi fun ifa ni agan kan ni toju omo won ifa aya ifa ni ika sini oma se oge kodi oge sise ku tori kole ba bimo
ifa pere fun enito da ifayi
ki elelyi orubo si eni ise ki
osi fi akuko adie bo esu ifan
omo iya meji ni oun bawi ki
won o rubo sieni won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie
Eko
Eja
Epo
Opolopo owo
Akuko adie
Epo
Eko
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju ewe oro ewe akisan ao lo ao fi se igbin meri lepo ni yo aowa foju imin ojo ao wa fit e odu ifa fofun olobara ao wa se adurosi ao wa je obe naa ao lobo awon ikarahun igbin yi mon eti odo fibasan
Ao toju ewe ajagun morase ao toju
ewe toto ao toju iyere ao wa bop o ao wa fi se eye etu kan lepo niyo ao w ate iyereosunni odufa ofin karan ao wa se adura si ao waye obe naa
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju awo imondo pelu sewe
Alupayinde ao wa jopa po ao wa po mon ose dudu ao wa fi we fun ojo meje
ao toju ori eye awo ati orieyeleao toju ewe ori ji ao wa gun gbogbo re papo ao wa po mon ose dudu ao wa mon
fi we laro laro titi ti yio fi tan
Explore Ifa
Ofun Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ofun Meji,Ofun Ogbe,Ofun Oyeku,Ofun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ofun Obara Odu.
