O
This Odu signifies the journey of perseverance and strength in overcoming challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Osa kanran
Orin kanran
Adifa fun kininun tin be laarin ota Ebo wonin ose
O si gbebo nibe o rubo
Nje kininun fi to gba ju
Eman sa kijo kijo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni ki elelyi orubo isegun
pea won kan gbogun ti
eleyi korubo kole ba se gun
enina kio fi akuko adire bo esu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meji
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Osa Kanran
Orin kanran
Adifa fun eegun
abufun eeru
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire laiku fun
elleyi pe ki elelyi orubo ki
emi re olegun tio fi oruko
kan rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Osa Kanran
Baba lawo awo lodifa fun awo
Awon tode orun bow aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire gbogbo fun eleyi ki
eleyi orubo ki ire ole bade fun ko fi ekumeji eja meji eye meji bofa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku meji
Eja meji
Abodie meji
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Yangi
Abori ku gu
Babalawo aje lodi fafun aje
Aje tode orun bowaye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peire ola fun elelyi ki elelyi orubo ki ore ole bam on gbo wore kio bo ori re pelo akuko adire kan kio si fi akuko adire kan rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meji
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju awo ikoko ao toju
ewe koko ao toju ewe sese
ao wa gun gbogbo re mon ose dudu ao wa mon fi ose naa we larolaro
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ISEGUN
Ao toju ori ejo ati oko atare kana o wa lopo ao wa gbe odo kale ao wa dojure de ao ta epo pupa yipo odo yi ao wa joko lelori ao wa fi ebu ifa yi si gere mokalelogun si arin ori onitoun ao wa fi iyoku la epo pupa lori odo yin.
Explore Ifa
Osa Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Osa Meji, Osa Ogbe, Osa Oyeku, Osa Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Okanran Odu.
