I
This Odu signifies the importance of wisdom and foresight in overcoming challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Iwori Bogbe
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Lala toroke ile nibo
Adifafun efufu lele
Ti o ni oun o mun oun
Ile je gbe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eleyii, pe ki eleyii orubo ki aye mon ba gba eto re lowo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemeji
Akuko adire meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni iwori bobobo
Babalawo ekolo
Adifafun ekolo
Ngbati nlo isale abata
Nitori omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii orubo
Ntori omo ko le badi
Olomo laye
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abo adie mejiEyelefunfun meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ona gburugburu gburu
Ejeka to wo bi aba
Ri ire nibe
Adifafun iwori ti nlole ree ko ire ba ogbe egbon nile
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki omo iya meji orubo ki won o le ko ire dele lati irin ajo Ki enikan osi mon soroju
Ki won o si mon ja arawon niyan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemeji
Agbeboadie meji
Epo at eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Iwori bogbe
Iwori bogbe ni ji je
Iwori bogbe ni munmu
Adifafun igunnugun
Ti nlo wo adaba lorun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eni naa ko mon se okanjua, ki eni ti ko si gbadun ko rubo ajinde ara re ki o fi aso ti oferan julo ninu aso re rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akape eran
Fun awon agbalagba
Odidi oruko kan
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ao toju ewe ajilekese ti o po dada egbo feru ao gun mon ose dudud aote iyereosunni iwori bogbe
Ao se adure si ao mon fi we lori okuta ako ni ojo ketaketa
Igbin to pinu merin, ewe sajeje topo ewe adurosusu, ao lo pelu iyere ao fi se igbin yen lepo niyo je, ao te iyereosunni oduifa iwori bogbe ao je ti abafe sun lale.
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju ewe ajilekese ti o po dada egbo feru ao gun mon ose dudud aote iyereosunni iwori bogbe
Ao se adure si ao mon fi we lori okuta ako ni ojo ketaketa
Igbin to pinu merin, ewe sajeje topo ewe adurosusu, ao lo pelu iyere ao fi se igbin yen lepo niyo je, ao te iyereosunni oduifa iwori bogbe ao je ti abafe sun lale.
Explore Ifa
Iwori Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Iwori Bogbe. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Iwori Meji,Iwori Oyeku,Iwori Odi,Iwori Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Ogbe Odu.
