I
This Odu represents the need for adaptability and resourcefulness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Iwori Ayoka
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Iwori ayoka
Adifafun ayoka
Ti nfomi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki orubo ntori omo ki osi mon fi omo yo eniti ko ti bimo
Rara
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbeboade merinEyeletitobi merin
Epo
Eko
Obi
Oti
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ilu winrin lawo ilu winrin
Ilu winrin lawo ilu winrin
Adifafun ajijobu
Tise omo iwori ayoka
Nje obi won o obi po
Owo awo rere lati
Ba obi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii o mon je ki obi o mon won nidi ifa re ki o mon ko obi si ori ifa re dada.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo obi
Akuko adie mejiEyelemeji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni iwori wokawoka
Adifafun igba
Igba nloko ailero odun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi omon gbo nkan ti awon babalawo ba n wi fun un ki o mon se aigboran ki ole ba jere aye.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Pepeye meji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Iwori ayoka
Adifafun ayoka
Onidi opengele
Eyi ti ofi idi dijale lahere
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii orubo ki o mon je pe won ole ku ro laarin ilu ntori isekuse re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko
Oruko
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE
Ori oruko ti won fi bo esu ewe awo yoyoy ewe ako mererin iyere won olopapo ao fise ori oruko yen lepo niyo
Idi esu na ni ao ti je obe na ao mon toro nkan ti abafe lasiko igbana
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ori oruko ti won fi bo esu ewe awo yoyoy ewe ako mererin iyere won olopapo ao fise ori oruko yen lepo niyo
Idi esu na ni ao ti je obe na ao mon toro nkan ti abafe lasiko igbana
Ewe segun sete ewe gbegi oju ode ao gun mon ose dudu ao te iyereosunni iwori ayoka ao sure si ao mon we ni ojo ketaketa
Explore Ifa
Iwori Ika is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Iwori Ayoka. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Iwori Meji,Iwori Ogbe,Iwori Oyeku,Iwori Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Ika Odu.
