O
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Idin osun
Idin owo
Idin ofojuba orunlatale anaa
Adifafun ori otola ateteniran
Igba ti n tode orubo waye
Ao toju ewe owu akese ao toju ewe akisan ao wa lopo lepo niyo ao wa fi se odidi okete kan lepo niyo ao wa se adura si ao wa je obe yi egungun okete tokuyi ao wa fi jo po mon awon ewe toku yi, ao wajo po mon odidi atare kan mon ao wa mon fi oti oyinbo lo larolaro.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire nbe fun eleyi sugbon awon aye o fe ma sele ni ni re
Ifa ni ki eleyi o mo feran obinrin kankan lo elelyi yo si bimo meta kan, ifa ni awon omo yii ni wongbija iya won
2
Ese Keji
Ese Keji
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Idin osun
Idin owo
Idin ofin ojuba orun latale ana
Labayin kiti ayin kiti
Adifafun awonrinwon aborikangin
Igba ti be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to dafayi korubo kole di olola kofi aparo bo ori tori ire ifa ni ire koni bo sonun lowo re
Ifa pere fun eni toda ifa yii, ifape ninu awon eleyi oun fi oju kere eni kan fo. Oun foju pe ko lese inkankan fun oun tabi ninu awon orere ifa ni komo foju di eyan ifape eni kan n be tin ja eleyi logun korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aparo
Eyele
Opolopo Owo
Akuko adie
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Idin rusurusu
Adifafun egbe aye abufu toru
Igba ti won raye lainite
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi, ifa ni oju aje nipon eleyi korubo kio le ba ni aje
Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni ibi kan laleyi ninlo ko rubo kole kore bo nibe
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe sapo ewe ogede agbagba ewe saworopepe ewe ina epo konu koho tio babo sile funrare, ao gunpo mose ao fi lofinda bi tupo ao ko sinu ike funfun ao ma fiwe
Omundun ewe pandoro ao lomopomo iyere ao fi se odidi igbin kan leponiyo ti oba jinnan ao su aso funfun ni o suka ao so kanoru ao se adun sini ihoho
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Egbo akerejupon mokanla ao jo odidi atare mokanla ao jo pomo arawon ao fi sin gbere meta meta si orikerike ara
Ewe sereyo egbo eti pon ola epo obo die odidi atare kana o jo po ao wa fi sin gbere yipo orun owo mejeji
Explore Ifa
Odi Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Odi Ogbe, Odi Oyeku, Odi Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Odi Irosun Odu.
