Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Odi Ose

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for cleansing and renewal.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/odi-ose
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Idin se Irele se Igi ogba se Keni o yomisi Adifafun Orunmila Nijo ti baba dako die lagbala

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi orubo omo ifa ati okunrin ati obinrin ni won o jo rubo naa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meta Pepeye funfun meji Akuko adie meji Eku Eja Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Idin sese Awo eja lo sefa fun eja Nijo ti n gbogun lo ilodo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elehun o mon gbokanle oogun etutu ni ki elelhun ogbokanle ki o mon yan koyan oogun laelae

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Okete Esun isu Akuko adie meta Atare meta Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Idin se Irele se Igin ogbase keni o yomi si Adifafun asinwin ile oba Abu foba panpa Won ni ki won o rubo Ki won o le baa lase lenu Won si gbebo nibe o won rubo Nje, osese imoko are Iti ifa bawi ni yoo se Moko are Osese moko are Iti oba bami ni yio se Moko are Osese o moko are

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe won ofi elelyii se olori nibikan ifa pe kofi pelepele se ki ipo naa le badi tie ki won le mon ponle nibi gbogbo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo igbin Aso funfun Akuko adie meji Agbebo adie meji Epo Eko Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Idin se Irele se Adifafun ase bagebage Nijo ti n momi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa peki elelyii o rubo ntori gbogbo nkan bi ajogun buruku tui o fem on sele si ki o mon fi ebo se awada kotete rubona

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

oruko kan lEBO agbebo adie meji eku ati eja fun ifa obi ati oti epo ati eko ewe abirikolo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN ewe abirikolo ewe alupaide ewe swegun sete odindi atare meta ao jo papo ao le ti okunna dada ao te ni odu ifa (osedi)

Videos

Watch Odi Ose teachings on our channel.

Explore Ifa

Odi Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Odi Ogbe, Odi Oyeku, Odi Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Odi Ose Odu.