Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Ofun Okanran

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the need for adaptability and flexibility.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ofun-okanran
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Afinju ejo niga agbon Ofinran eku nitona ja Oja ni obe kun Lonan korele lo le ma bewa Adifafun olugedo elelyi tio teko lenpe omo asagijo Omo arin gijo Omo afodi oko tale fo mo ga moga Igba tinbe laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa nip e oun pere aje pupo fun eleyi ebo ni ki eleyi ose kole bani aje lowo kio si lobo aje pelu pepeye meji ati oyi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji Oyin Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Afefere nidun mope pere mo Pepere aran gojo gojo nidun Moko moja Moko mojo moko Mojo mokomojo aran Adifafun ofun abufun olokanran Nijo won nlole kanle Ija

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire apesin fun eleyi ki eleyi orubo ki o le bari eni pe si kio lofi ori eye osi fi akuko kan rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ori eye osin Agbon kan Akuko adire kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Epepere nidun Epepere epepere Aran gojo gojo nidun mo komojo mokomojo Mokomojo aran AdifafunKoritii sunkun omo lo bode oyo Ebo won ni ose O si gbebo nibe orubo Nje,korio are weyo Fun mi lomo kan kin gbesere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire asegbe fun eleyi ki eleyi orubo pe gbogbo oun ti bASE yio mon se ni ASEgbe kio rubo pelu aja kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aja kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Igi gbigbe abi akuo tutu nini Adifafun lalule Abufun lauluoko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire gbogbo fun eleyi lati okore ebo nikose ki o si lobo orisale pelu opolopo igbin ati eye etu kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan Opolopo igbin Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju itanna tanna powo ao lo pelu iyere ao wa mu eran monlu ao gesi mokanle ni ogoji kekere ao wa seni epo ni yo ao wa se adurasi ao wa je obe naa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju awo ilu duru ta bi awo ilu ara ao lo ao po mon ose dudu ao wa mon fiwe larolaro

Videos

Watch Ofun Okanran teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Ofun Meji,Ofun Ogbe,Ofun Oyeku,Ofun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Okanran Odu.