Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Ofun Ose

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for cleansing and renewal.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ofun-ose
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ororo ni meran Adifafun Molaika Eyi ti o paa gbonrin tan Ti yoo fi itan re ase

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifayi ki eleyi orubo ki ire ola ba to lowo kosi lo bo oogun ko si mo se ahun komo se ore fun awon eyan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Eye le Igbin Eko Epo Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ofun lese lese Awo ile onilese Adifafunonilese O ji, oni oun o marun tise oun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifa yi ki elleyi orubo nitoriarunowo ifa niarunkan nse eleyi ninu ara ifa ni arun owo ni koruko ki arun naa ola balo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

OrukoEyeleAgbado Epo Eko Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ofun suhin Babalawo arugbo Lose fa fun arugbo Nijo ti arugbo lo soko ganrin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi ko rubo ki osi mon kanju ore pe ire gbogbo yio wa fun kio lobo orire pelueyelekio sifi akuko adire meji rubo fesu odara

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie mejiEyelekan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ofun se Babalawo aje Lo sefa fun aje Aje n tode orun bowaye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa nip e ohun pe ire aje fun eleyi ki elelyi olobo aje pelu eye etu meji kio si fi oruko boesu odara

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu meji Eran oruko kan Epo Eko obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe ela ajagun morASE ewe akisan iyere ao wa lo gbogbo re pao ao wa fi se eran okiri ewure merindinlogun je ao wa se adura si ao wa je obe naa.

Videos

Watch Ofun Ose teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Ofun Meji,Ofun Ogbe,Ofun Oyeku,Ofun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Ose Odu.