O
This Odu represents transformation and the end of a cycle, emphasizing renewal and rebirth.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Ofun Oyeku
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ofun ye funye sowokoto
Adifafun fun Eta
Ti n somo olojontu
Igba ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo
Kolebaa nin segun
Nintori wiope aarin ota
Leleyiwa
Ko gbebo nibe o rubo ki won oman baa papa loju orub
Kosi fi ogede ominin bofa
Pelu obi meji
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Ogede ominin
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ofunye funye sowo koto
Baba lawo Ila
Lodifafun Ila
Ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo
Nintori wipe aarin ota leleyiwa
Awon ota tiro elelyi pin wipe
Ko lee jenkan kan laye re man
Awo otan ba inkan elleyi je
Keleyi ofi opolopo ila kun
ebore ru kole baa segun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Opolopo ila
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ofun yeeye min ye
Adifafun arugbo
Tin loko yanrin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyo orubo
Ire ajenbo kun eleyi
Paa paa ju lo ifa ninre ola
Fun eleyi lenu isere
Eleyi yio la lenu isere
Lodun yi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Efo yanrin
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ofun yee ye minye
Adifa fajeolokunosineepe
Eyi ti o lala la tiwon onin le tenin fun mo Ebo won ni ose
O gbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
Ebani ni jebutu ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifanin ke leyi orubo
Ire olan bo sun elleyi
Keleyi osi bo aje nin
Opolopo ekuru funfun
Eyin ogede ominin oyin wara
Obi ati oti nintori
Eleyi yiola tire ola nan yi osi po
Gidi gidi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Egbo efo yanrin
Egbo tude
Egbo inanbiri
Eeru alaman merindinlogun
Aogun po man ose
Ao man fiwe
Alunosa funfun
Ewe jiwinin
Irun ori afin
Ao lo gbo gbo repo
Ao da sinu adi gban
Aoda lofin da toba wuwasi
Ao man fi para
Explore Ifa
Ofun Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Ofun Oyeku. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Ofun Meji,Ofun Ogbe,Ofun Iwori,Ofun Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ofun Oyeku Odu.
