O
Ogbe Ogunda is a significant Odu in Ifá Divination, symbolizing blessings, fertility, and the power of duality.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Koko eku nio tororo kanle
Adifafun orunmila
Baba o fi ojo ose saya
OGBE SA
Okiti pete awo asagande
Adifafun asagande
Tin mo mi oju so gbere aje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifa yi ki elelyi orubo ni tori aje kosi ma se ose fun ifa dada ki I re aje ole ba defun
Ifa pe ire fun eni toda ifa yi ko rubo ifa ni oju ajo pon ifa ni ko fi oti bo fa ko si gba oti naa lawinni ko gbodo fi owo lara leyin toba bofa tan ni kolo san owo naa.
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ibinu ose kan fun ni
Suru ni baba iwa agba toni suru
Ohun gbogbo loni ajogbo ajato
Ajaayefa gbindingbindin bi eni tin la oyin
Adifafun orunmila
Baba n sawo lo sode iwo
Patako efan abi eda gbeke
Adifafun agbonrin galaja
Tise omo olugbo
Igba tin raye alaiku
Fawo wale
Faleke wale
Adifafun etiponola tise Omoalahoro
Igba iwase
Igba tin momi oju sogbere ire
Ogbe tomopon
Abiamo sun mosi
Abiamo sunmosi tidi ala
Adifafun ojogbojokun
Ti n sawo rele olokun aweroro
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifape ire fun eni to da ifayi ifa ni koma ni suru pe ire nbo fun ko ma ma binu ko ma ko egin ifa ni to ba rin irnajo pe kolo sugbon gbogbo oun tobari nibe ko gbodo fise ibinu
Ifa pe ire fun eni toda ifa yi ifani korubo si enu isere ifa ni awonkan nso lenu isere bi won o se mun ifa ni ti babare banbe laye komo ki laro laro koto losi enu ise ti ko ba si babare lare laye kobo babare ifa ni ori baba ni oyoninu ogun omo araye.
Ifape ire fun eni toda ifa yi ki osi rubo ki ire ola bato lowo ki osi ma jinnna si oso babare tori ire wa fun nibe.
Ifa pe ire fun eni toda ifayi korubo ifani irinajo kan ni elleyi felo korubo ko le ba ko re bo nirinajo.
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Arogbodo lefo eerowo ni ti tete
Adifafun onidere moja
Omo afi gbin sebo ogboo
Adifafun oni dere moja
Omo a figbin sebo omo
Igba tin momi oju sugbere ire
Ogbe sasa
Adifafun peregun
Ti omo araye omoro laro pin
Omodin nio mofeda
Atanpako nio molete
Eyigunju won nikan nibe leyin tin topon se
Adifafun enlojo igi oko
Won raye alaniku
Ogbetomopon
Abiamo sunmosi tidi ala
Adifafun yanmoti
Tin loko ailero lodun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ki elleyi o rubo ifa pe oun pe ire aiku fun oun si pere omo ko figbin ku eboru
Ika pe ire fun eni toda ogbe sa ifa ni ki orubo peawon omo araye nro laropin
Ifa pe ire fun eni toda ogbeka ki elelyi orubo ifa ni ounpe ire aiku fun ifa ni ko ni bawon kuku owowo
Ifa pe ire fun enmi toda ifayi ifa pe ire omo fun ko sibofa ni ije imun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin
Akuko
Opolopo owo
Akuko adie
Opolopo owo
Oruko kan
Akuko
Opolopo owo
Eku eja aboadie opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Kukuduku pete nana ki eerin kan
Agbado agbodo egberin sepeteri
Adifafun elelgunmojo
Omo olowo eyo
Igba ti n momi oju sogbe ire
See wele,
Se wele
Adifafun gbogbo okookanle nirunmole
Won gbogun lo
Ilubinrin won lo ni bee niwon riwon mu
Adifafun orunmila baba wo ogun ilubinrin
Ogbe karele omo osin
Ogbe ka rele omo ora
Ogba karele omo ogun lele alede
Adifafun aje tin torun bowaye
Ogbe tomopon
Abiamo sunmosi
Abiamo abisunmosi jangele jangele
Adifafun obi tin sunkun omolo si okiti efan
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni to da ifayi ki elleyi o rubo nitori ola ifa ni ounpe ireaje fun leleyi korubo kire aje ole bade fun
Ifa pere fun eleyii, pe ebo ni ko o ru yoo sila ti yoo lu lenu ise re, sugbon ki o ma ni okanjua.
Ifa pe ire fun eni toda agbeka korubo ni tori aje ki aje ola ba to loowo ko si ekuru funfun bo aje ko si rubo kole bani isinmi
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ifa ni oju omo upon elleyi korubo yo di olomo laye ko fi agbebo ad bo fa.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe okika efun osun aojo po mo arawon ao ro sinu ato ao pa akuko kan si ao ro ejere si ao ma fi oti sinabu lo larolaro.
MEDICINE TRANSLATION
La hierba de okika, efun sustancia blanca en polvo, osun la sustancia roja en polvo se mezclara y se derramara en un guardia medicinal matara a un gallo y le arrojara toda la sangre y uno se la llevara con vino shinarp todas las mañanas.
Ewe oju oro osibata obere omi okun yanrin oku yanrin osa eru Alamo ao gun gbogbo re ponmo ose omi okun yi lao fipo ao kosinu ike funfun ao ma fiwe laro laro
Ewe rekureku ewe ogo ewe omini ao jo po ao ro si ibi kan ao ma fi oti lo larolaro.
Ewe ominsin minsin ita kun ao lomo iyere ao fi se eyin adire merin leponiyo ao fiyerosun te odure.
MEDICINE
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe emun, igi ti sangopa aojo po mo odidi atare kan ao fisin gbere kan si arin ori.
MEDICINE
Ewe imi eran eru Alamo ako okuta were mesan ao gunpo mo arawo ao wa pomo ose ao ko si ori okuta ako kan ao ma fiwe.
MEDICINE
Ewe idi, odidi atare kan ao jopo ao ma fi omitutu lo larolaro.
Tangiri odidi kan opolo aye kan ao jo po mo odidi atara kan ao ma fi fo eko tutu mnu laro laro.
MEDICINE
Explore Ifa
Ogbe Ogunda is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Iwori, Ogbe Odi, Ogbe Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogbe Ogunda Odu.
