O
Ògbe Ìrètè Excerpt
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Okomelero ona meleye
Owo gbogbo lemise
Balabatin labati
Adifafun okunrin karabata karabata
Ti n lole bawon gbe di agba oti
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ekan nan owo mi nijata
Erigimi nijobi erigi jobi
Kotomuti aida inu fifo ni tofo inu fifo ni todin Adifafun ajisebo
Ti i se omo bibinu agbonniregun
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Akuko toko lana ikore loko
Adifafun erin tin sunkun pohun oni ola
Akuko toko lana iko re loko
Adifafun efon
Ti n sunkun pohun koniyi
Akuko toko lana ikore loko
Adifafun asin tin roko
Lo leela ebo won ni won o se
Won sigbebo nibe won rubo
Nje erin lola efon niyi esin nikan lo loko lola.
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ajinigboro
Aringboro
Oburinburin bomi igboro boju
Oburin burin bomi igboro sinse
Emon igbo ni sare gonto gonto
Adifafun orunmila
Baba nlo le bawon fowo irukere mu le nigboro Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Nje aje tin o ni n ko nigboro lowa oore mi gbogbo Nigboro ire gbogobo temi ni n ko
Ni gbooro lowa oore mi gbogbonigboni.
Explore Ifa
Ogbe Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Iwori, Ogbe Odi, Ogbe Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogbe Irete Odu.
