O
This Odu signifies the power of patience and strategic planning.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Okanran roro ibeje
Adifafun orunmila
Baba ofi ikoko pete segun otare
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pere isegun ki elelyi o lo fin ewa pete pese fun awon agba ko si fi eku eja abodie bofa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abodire kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire laiku fun eleyi ki eleyi olobo ifa pelu eku meji eja meji abo adire meji
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku meji
Eja meji
Abodie meji
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Okanran rusurusu
Adifafun erinlelojo erun nijo
Ti swon tode orubo waye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Pepeye kan
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao toju ewe areyin
kosu pelu iyere ao wa fin se
eyele kan je lepo niyo ao
wa se adure si daradara
ao wa je obe naa
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju okiti ogan ao toju aran afe ao wa lo meji ji papo ao wa po mon ose dudu ao wa fi we lale fun ojo meje
Explore Ifa
Okanran Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Okanran Ogbe, Okanran Oyeku, Okanran Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Okanran Irosun Odu.
