Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Okanran Otura

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of strategic planning.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/okanran-otura
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okanran tuatuatua Adifafun owo nijo ti lole gbe Naamu niyawo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Onigba ilekun Olagba ilekun Gbongbon ileku kojekan onirun Latari Adifafun ati nu mon ti se omo Bibi inu agbonmeregun Won ni korubo ni laiku arare Ogbebo ni be orubo Nje orumila kon fi atunu Man omo ni fin ku paje Oun iku meji ati imule
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okanran tuatuatua Babalawo enu Losefa fun enu Igbati be lari ota
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Okanran tua dasase Abi ise warawara Adifafun orunmila ire gbogbo lo lo de Kowo le EBO ni won ni kose Osi gbobe ni be orubo Nje aje loto tikode ko Ifa owinrinwin ede loni kode Ire gbogbo tolo ti kode Ko ifa owinrinwin wede loni kode

Videos

Watch Okanran Otura teachings on our channel.

Explore Ifa

Okanran Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Okanran Ogbe, Okanran Oyeku, Okanran Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Okanran Otura Odu.