O
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in navigating life's challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Osa Ika
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Osa Kadi
Orin kadi
Adifa fun salubata in je laarin ota
Osa Turu
Ipon turu
Adifa fun ipon
Tin gbogun lo ilobe
Alawo
Alawo
Adifa funorunmilaIfa nbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo
ibikan lonloyi
ota po ninbe
yio segun won
Keleyi orubo
ibikan laleyi n loyi
korubo ota nbe nin nbe
Ifa fore isegun lori ota fun eleyii, pe ebo ni ko maa se, pe eleyi yio segun ota re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Bata
Agbado
Owo.
Epo
Eko
Ipon tiwon tin bube
Agbado
Owo.
Epo
Eko
Awo tan ganran
Agbado
Owo.
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo
Ire isegun
Ota fin
Ire isegun
keleyi orubo
ota n lakan ree feleyi
oju eleyi lo sugbon
eleyi ose gun re.
Ifa pe ki eleyi orubo, pe ibikan leleyi n loyii pe awon ota ni koninde pe keleyi orubo yio lore yiobore
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Akuko adire kan
Owo.
Epo
Eko
Obi merin
Agbado, Owo.
Epo
Eko
Agbado
Akuko die kan
Owo.
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo
oju ajenpo eleyi
ire ajede fun
Ire aje
keyi orubo
kire aje ole ba
to eleyi lowo
Ifa pere fun eleyii, pe ori re ni yoo sere aje fun eleyi koman rubo nin gbogbo igba ti o bafe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
EkoEyelemeji
Agbado
Owo.
Epo
Eko
Agbado
Owo.
Epo
Eko
Agbado
Owo.
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Osa Kadi
Orin kadi
Ofo feere omori odi ika gun
adifa funorunmilaIre gbogbo nlo lode okan kan oyalewa Ebo wonin ose
sirubo Ero ipo Ero ofa
Ewa banin bola ba peregede
Osa tuuru
Ipon tuuru
Adifaje
Tin tode orun bowaye
Sigidin Gbari
Adifa fori
Tin lo le agbado
Awure lodo orisa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Oju ajen pon
eleyi korubo
ajen bo fun eleyi
Ifa nin re aje
ebo nin keleyi ose
ajenbo feleyi
Ifa ni ori eleyi ni yoo sare aje fun un, pe orire nin kodiman
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe omundun isin
Ewe sikiminin
Iyo
Oyin
Ao gun gbogbo re po manose
ao man fiwe
Oga aaye kan
ori ofafa kan
ori oka kan
Ao jopo ao ro sinun ado ide kan
ao man fifoko mun
Explore Ifa
Osa Ika is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Osa Ika. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Osa Meji,Osa Ogbe,Osa Oyeku,Osa Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Ika Odu.
