O
This Odu highlights the need for patience and perseverance in achieving success.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Osa Irete
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Osa rete
Orin rete
Orinrin rete rete
Wode ijebu
Adifa fun peepeye
Tinbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ibi kan leleyin lo yii
Koruno yiori oore munbo
sugbon korubo ota
kiwon oman baada
oorere lonan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Alabaun kan
Owo.
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Oodu gbiri
Ikoko man yin so
Adifa fun baje
tin somo orisa gba owujin
igba tin be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo
aarin ota lowa
kosibo orisa
orisa nin oba segun ota
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ao fi igbin meji bo orisa
Oti
Obi
Epo
Eko
Agbado
Owo.
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ita Gbangba
Nin ose kan aasesi
Adifa fun omo enin kanjiya
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo
iya tin je bo tipe tipe
asiko ire aje eleyi to
eleyi yio la
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Obi meji bo aase ati akuko adire kan
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Osa Rete Orin Rete
Adifa fun kin somo
Tii soman oloro kan atijo tijo
Igba tin fomin oju sogbere ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ire eleyi kanree
toti silo korubo
ire aje eleyi n pada bowa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe aje
ewe omo nin gede gede
opolopo irun oya
Afara oyin
odidi atare kan
Ao jopo oyin lao man fi lo
Explore Ifa
Osa Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Osa Irete. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Osa Meji,Osa Ogbe,Osa Oyeku,Osa Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Irete Odu.
