O
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness in personal growth.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Osa Iwori
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Osan wole
Iwori n wode
Adifa faja tiisomo
Iya ofafa
Igba tinbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Aarin ota
Leleyi wa korrubo
Kole baasegun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Akuko die kan
Agbado
Owo.
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Yangi abori kugu
Adifafun baayanrin
Tinbe laarin otaa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Omo iya eleyi
Gangan lotare
Korubo yio segun re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akukodie kan
Ao fib o baayan rin
Pelu obi meji
Epo, eko, agbado, owo.
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Osa n wole
Iwori n wode
Adifafaje oun Omo
Won tode orubo
Bowaye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe Ire aje
Fun eleyi lati okeere
Korubo kole baate lowo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo.
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Yangi abori kusu
Adifa fabajo
Tii somo orisa owujin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Omo orisa nin
Eleyi komanbo
Orisa kire ajere oleetelowo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ao fi igbin merin
bo orisa ati obi meji
Epo, Eko, Agbado, Owo.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe eye oba
Ewe owu akese
Aidan
Ao gun po manran won
Ao po po man ose
Ao ma fi we
Explore Ifa
Osa Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Osa Iwori. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Osa Meji,Osa Ogbe,Osa Oyeku,Osa Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Iwori Odu.
