Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Osa Ofun

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of balance and harmony in life's journey.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/osa-ofun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Won ni wono mo fan ti olu Won fan ti olu igba erin si Won re gbio oni koko bo jo Won ni won omo fan wo lu Fan wan fanwolufan igba Efan si won releju fo fobo Adifafunorunmilababa nbe Mnirangun ota ebo won ni o se Osi gbe bo nibe orubo Iya alado ewi yan nan mi alaworosasa oyan nanmi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda fayi ifa ni ki elelyi o rubo ifani arin awon ota ni elelyi wa korubo kole ba se gun wo kosi fi iyan bo ifa kiwo oto gun iyanyi won o koko mu isu bi meji sinu abo won owa fi epo pupa si enito dafayi yowa je ni idi odio

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko Adie Igbin Alabahun Eko Epo Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ekan ni o jeraye run be nile olonje Adifafun olugbonAgbeomoagbegba losi Omo olugbon saki Igba ti n momi oju sogbere ire Ebo ni won ni ose O si gbebo nibe o rubo Ruru ebo Eru atuka esu E wa bani nije butu ire Ofun pa perengede Adifafun aha Tirogun ajee amunye Ebo won ni o se O si gbebo nibe orubo Ruru ebo Eru atuka esu E wa ba mi laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifayi ika ni oju aje ni pon eleyi ki o rubo kole ba ni aje ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni ki elleyi o rubo ko le ba segun ifa niogunpo fun elelyi korubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

EyeleEye etu Pepeye Eko Epo Opolopo owo Akuko adie Alabahun Igbin Eko Epo Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Te ileke se date onula Aso igba se daso oko Adifafun ina oni oun o joye olonroro ate ileke Se sate onula aso Igba a sedaso oko Adifafun Orun oloun o joye olonroro ateleke se date onula aso igba seda So oko Adifafun Osupa olun ojoye Olonroro Ebo won ni won o se Osupa ni kan ni n be leyin omo olonroro Amun ina joye obaye je Orun ode omo olonroro amun orun joye obayeje Osupa de omo olonroro amun Osupa loye aye gun Ofun ka Ofun ko Adifafun okokomiyele Abimo mowase Igba ti momi oju sogbere omo Ebo won ni ose O si gbebo nibe orubo Nje, badie ba se koko Omo loyekle n sun kun pe

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifa ki elleyi o rubo ifa ni ounoere oye fun elelyi ko si mo roro mo awoneniyanifa pere fun eni to da fayi ki eleyi orubo ifa ni oju omo ni pon elelyi korubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

akuko adieeyeleeye etu eko epo opolopo owo Agbebo adie Eku Eja Eko Epo Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ani ki won mo fan ti olu won Fan Ti olu igba erin si won re gbo Olu koro koro mojo won ni won o mo fan Wolu fan won fan wolu Igba efan ya won ree eleju gbogbo fo ayanu ayanu nijoyun omo kan o dueo Adifafunorunmilati iku po kankan le irunmola yi aye EBO won ni o se osi gbebo nibe orubo Mee ti bawon yun Mee tiba won ree Koro koro ide kimomo bawon yun bo orisa Ofun won kaka Oniwon koko Adifafun agbaku oni se oba Inanaja eero Ebo won ni ose O si gbebo nibe orubo Ruru ebo Eru atuka aesu E wa bani bola ba perengede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun elelyi ki o rbo iku owowo ifa ni eleyiosunoorun korun osi lala kala kio rubo pe apoere iku ni ifa pere fun enitoda ifayi ki elelyi orubo si enu isere ko lebala ifani tielelyi ba wa labe enikan tinjisefun kio rubo kole balanibe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Epo Eko Opolopo owo Ikode Eye etu PepeyeEyeleEko Epo Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao ju ori eye igun toju ori eye asa ao toju ori eye lekeleke ao toju efu osu ao wa jo gbogbo re papo ao wa gun papo mon ose dudu ao wa fui owo eyo merindinlogun gun ose naa lori ao wa mon buwe laro laro AWURE Ao toju ewe ela ewe akisan ao toju iyere ao wa fi seeyelefunfun meta lepo niyo ao w ate iyere osu ni odu ifa ofun ohun ika ao wa se adura si ao wa je obe yiegungunre tobakun ao lobo mon idin esu

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju ewe oraba ao toju ewe eru ao toju ori aja ao wa jo gbogbo re papo ao wa mon fi pese fun awon iya mi pelu eran akape ati epo pupa ao mon so gbogbo ohun ti aba fe si Ao toju epo igin winla ao toju ewe aje obala ao toju ewe lorugo ao toju igbin kana o wa gun gbogbo re papo mon ose dudu ao wa mon fiwe

Videos

Watch Osa Ofun teachings on our channel.

Explore Ifa

Osa Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Osa Meji,Osa Ogbe,Osa Oyeku,Osa Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Osa Ofun Odu.