O
This Odu signifies the power of transformation and the wisdom to navigate challenges.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Osa Ogbe
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Salumin kin salu o
Sisa lominun Agbada Salurawon
AdifafunorunmilaBaba nbe larin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo nintori
Ajenbo feleyi,
Ibikan leleyii nlo pe yoo rire munbo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Epo
Eko
Agbado
Opolopo Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Kamun peki kafiko peki
Kamun peki kafiko peki
Kafigi ajameji korawan
Peki peki peki
Adifa funesu odaraWon deru kale
Won ni omangbe karode – orun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo awon ota ti n pete ika kale fun eleyi.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abefele kan
Akuko die meji
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
OSA OGBE
Osalufogbejo
Aso ayaban tube
Ninpopo
Adifufun sekere
Tinsawo rode oyo
Ebowonin ose osirubo
Eropo
Ero efa
Ewa banin bola ba peregede
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE (WEALTH)
Aofi akara bo esu pelu obimeji epo pupa, ao wa rojo si akara yi ao lofi sori esu.
Explore Ifa
Osa Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Osa Ogbe. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Osa Meji,Osa Oyeku,Osa Iwori,Osa Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Ogbe Odu.
