O
This Odu signifies the power of transformation and the need for adaptability in the face of change.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Osa Ose
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Osa se
Orin se
Aase ti baba omo fi sile
Loman un sole
Adifa fun eegun
Nin jo oun orisa jon sota
Safun min
un fun o
eekan nin ofibi booroboro wole
adifa fun alagbede okankan
igba ti nbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ota kan ree fun eleyi
korudo yiosegun re
sugbon ki eleyi onin suuru O
koman kanju yio segun
Keleyi orubo
awon ota nin lara
yio segun won.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko Olele, Obi
Orogbo Ataare,
Oti bo eegun
Epo, Eko,
Agbado Owo.
Epo
Eko
Agbado
Akuko die kan
Owo.
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Osa se
Orin se
Aase ti baba omo fi sile ninun sole adifa fun oro tinbe laarin ota ebo wonin ose osirubo
eropo ero ofa ebanin laru segun
Safun min
Un ofun o
eekan nin oti bi boro boro wole
Adifa fun oosa nla osere mangbo
Nijo tin sawo relu igodo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa nin re isegun
fun eleyi
ebon in komanru
Keleyi orubo
ibikan nin loyi
awon ota nin koninde
ebon in kose yio lore
yio bo re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aofi ogiri bo oro ewa ososo, obi ati oti Aofi epo, eko, agbado ati owo rubo
Epo
Eko
Agbado
Owo.
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo
eleyi ola
ti enin kan onin ridi owo re
Ifa pere fun eleyii, pe keleyi orubo, pe ire aje renrubo lai pe, pe ebo ni koru yoo nire gbogbo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Panbe lawe
Panbe lawe
Adifa fe fegun
tin sawo rebi atoke doke
Osafun yinyin
Adifa funorunmilaBaba ji baba orowo kan ayo nan
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa nin re aje
nbo feleyi
eegun nin kolobo
Keyi orubo
Ko man kan ju o
ire re fee detan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ao fi eko, olele, akara, obi, ati oti ao fib o eegun Ao fi epo, eko, agbado, owo ao fi rubo
Epo
Eko
Agbado
Owo.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe igba
Ewe oori
Ewe yeepe
Ao gun gbogbo re po man ose
Ao man fi we
Explore Ifa
Osa Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Osa Ose. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Osa Meji,Osa Ogbe,Osa Oyeku,Osa Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Ose Odu.
