Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Iwori Ika

Iwori Ika also known as Iwori Ayoka
Aliases:Iwori Ayoka
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for adaptability and resourcefulness.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/iwori-ika
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Iwori Ayoka

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Iwori ayoka Adifafun ayoka Ti nfomi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki orubo ntori omo ki osi mon fi omo yo eniti ko ti bimo Rara

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboade merinEyeletitobi merin Epo Eko Obi Oti
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ilu winrin lawo ilu winrin Ilu winrin lawo ilu winrin Adifafun ajijobu Tise omo iwori ayoka Nje obi won o obi po Owo awo rere lati Ba obi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyii o mon je ki obi o mon won nidi ifa re ki o mon ko obi si ori ifa re dada.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo obi Akuko adie mejiEyelemeji Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni iwori wokawoka Adifafun igba Igba nloko ailero odun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi omon gbo nkan ti awon babalawo ba n wi fun un ki o mon se aigboran ki ole ba jere aye.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meji Pepeye meji Epo Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Iwori ayoka Adifafun ayoka Onidi opengele Eyi ti ofi idi dijale lahere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyii orubo ki o mon je pe won ole ku ro laarin ilu ntori isekuse re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko Oruko Epo Eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

AJE Ori oruko ti won fi bo esu ewe awo yoyoy ewe ako mererin iyere won olopapo ao fise ori oruko yen lepo niyo Idi esu na ni ao ti je obe na ao mon toro nkan ti abafe lasiko igbana

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ori oruko ti won fi bo esu ewe awo yoyoy ewe ako mererin iyere won olopapo ao fise ori oruko yen lepo niyo Idi esu na ni ao ti je obe na ao mon toro nkan ti abafe lasiko igbana Ewe segun sete ewe gbegi oju ode ao gun mon ose dudu ao te iyereosunni iwori ayoka ao sure si ao mon we ni ojo ketaketa

Videos

Watch Iwori Ika teachings on our channel.

Explore Ifa

Iwori Ika is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Iwori Ayoka. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include:Iwori Meji,Iwori Ogbe,Iwori Oyeku,Iwori Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Iwori Ika Odu.