I
This Odu highlights the need for courage and determination.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Iwori Aweda
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Iwori aweda
Eda ogbogun ebo ni
Ifa ni ka mon se dada
Adifafun aweda ti o gboju
Le oogun ju ebo lo
Nje iwori aweda,
Eda ogbogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyii
O mon gboju le oogunEtutuni ko mon se
Dada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Agbeboadie meji
Okete kan
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni iwori aweda
Eda ogboogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire lati ipase obinrin fun eleyi, Ifa eleyii si nwa obinrin korubo daada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbeboadie meji
Eye etu meji
akuko kan
Obi
Oti
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni iwori wo oun
Rere da
Iwori wo oun rere da
Ifa bi o bada rere tan
Ki o se rere ku fun mi
AdifafunorunmilaBaba nfomi oju sogbere aje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii rubo ire gbogbo ki ire ole to lowo ki osi rubo nipase omo iyare kan ti yio laa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemeji
Akuko adie meji
Eyeetu meji
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Iwori aweda
Eda o gboogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon bo ori re dada ki o mon gbekele oogun nkan ki o si mon peese fun awon agbalagba dada kosi mon rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Akuko adie mejiEyelemeji
Okete
Ki ofi eye etu kan
Bo ori re pelu obi ati oti
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori okete meta ewe mon fowo ba omo mi pupo odidi atare meta ao jo papo
Ao pe ifa si ao mon fi fo eko tutu mun lalelale
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ori okete meta ewe mon fowo ba omo mi pupo odidi atare meta ao jo papo
Ao pe ifa si ao mon fi fo eko tutu mun lalelale
Ewe aje pelu ewe etipon ola ao lo papo ao fi se igbin meji ao se adure si dada ao je gbogbo re.
Explore Ifa
Iwori Ogunda is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Iwori Aweda. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Iwori Meji,Iwori Ogbe,Iwori Oyeku,Iwori Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Ogunda Odu.
