O
This Odu represents the need for adaptability and resourcefulness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Obara ka kise oun te
Baba lawo ti n be nibe
Ni o gbofa
Adifafun alakan ti n lo
Eti okun lobi yaya lomo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo ntori
Omo ifa si ni pe
Ibi eti omi ni omo wa
Fun eleyi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie merin lebo
Eyele merin lebo
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ojo oganjo
Ni ta ogiri sasas lese
Adifafun tisan
Ti nlo le bo lowo ogun
✦
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Okete meta
Agbebo adie meta
Ao fi eku ati eja pelu agbebo adie bofa Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Obara ka ki se oun te
Baba lawo ti nbe nibe
Ni o gbofa
Adifafun sango olukoso laalu
Banbi arigbota osegun
Igbati nbe laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o se etutu
Aseyori ninu aye ki aye
mon ba mon da laamu ju
Kole ni isegun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie fun sango
Agbobo adie fun ifa
Pelu eku ati eko
Epo ati eko
Akuko adie fun ebo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
OBARAIKA
Firifiri ni won roju egungun
Adifafun olobare
Ti se omo iya ika
Igbati won nlo oko ailero odun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki omo iyameji
Orubo ntori ogun tofe
Ko won papo lekan naa
Ki won si mon se
Aigboro sirawon lenu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko lebo
Pelu okete fun
Awon agbalagba
Epoati eko
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Yepe ipile ile ao lo pelu atare eyo 9 fun okunrin meje 7 fun obinrin ato ni obara ika ao a pe oun re si ao fi sin gbere si orikerike ara wa.
Explore Ifa
Obara Ika is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Ogbe, Obara Oyeku, Obara Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Obara Ika Odu.
