O
This Odu emphasizes the importance of resilience and strength.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Bi babalawo gbofa
Bi ogbofa eje kafi
Obara okanran lowo
Obara okanran
Kise ifa afi lande
Adifafun orunmila baba nsukun
Alailenikankan
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon sope
Oun oni eni kankan ki
Orubo ki awon eeyan le
Mon pesin laye re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye osin kan
Eyele m,erin
Eye etu meji
Epo ati eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Bi mo leku kinku
Obara okanran
Bi molerun ki nrun
Obara okanran
Adifafun gudugudu
Tise omo leyin bata
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki orubo ki aje
Ole wawa pelu gbogbo nti obafe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele merin lebo
Eku
Eja
Pelu agbebo adie kan
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Obara kanhinkahin
Kanhinkahin womun
Adifafun kanhinkahin
Kanhinkanhin ntode orubo
Bo wa sile aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki elelyi orubo
Ki aye le ba tie mon
Yato larin aye
Ki osi rubo ki aye le mon beru re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Eyele fun meji
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
OBARA OKANRAN
Bi moleku ki n ku
Obara okanran
Bi mole run ki nrun
Obara okanran
Adifafun kanna kanna
Kan na kanna n torun bo wa saye
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isegunori eye kan nakanna eyo kan
Yio jo pelu ewe apada
Pelu odidi atare kan
Yose adura sio yio mon fi mu ko tutu
MEDICINE
Explore Ifa
Obara Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Ogbe, Obara Oyeku, Obara Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Obara Okanran Odu.
