Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Obara Oturupon

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of introspection and self-discovery.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/obara-oturupon
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Kafi igi lu igi Kale ba gbo ohun igi Kafi ope lu ope Kale ba gbo oun ope Kafi obara oturupon sode Kaleba gbo oun ti fa nwi Adifafun yeye kini nbe Nikunre igbati nfomi oju Sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleye orubo Ntori omo ifa si ni omo Ti eleyi se bi yi okunrin ni omo naa Adeyi ni oruko re omon je

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meta Ni ebo pelu eku ati eja Eko ati epo pupa
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Obaratokutoku Adifafun won ni Itoku magbon ti isale oja Nibi ti won ti nko owo ra oko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo Ki won o le mon fi Ounrere wa kaakiri Papa bi oko tabi aya

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meji Akuko adie meji Eyele kan totobi Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Obara otokutoku Adifafun magbon ti sale oja Nibiti iku ti npa won rogba rogba Toku ti npawon rewerewe Bi eni pe won ji onje iku je ni

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki won orubo si Inu ile tabi inu ilu Ntori ogun ki ogun mon ba Ka won mon le Ki iku mon ba mon pa won nikekere

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko lebo Ewure fun ifa Okete fun awon Agbalagba Eko ati epo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Kafi igi lu igi Kale ba gbo oun igi Kafi ope lu ope Kale ba gbo oun ope Kafi obara oturupon meji lu Arawon kale ba gbo Nkan ti ifa nwi Adifafun orunmila Baba njaye elekoko bike

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo Ki omon ba jaye ele Ki ara ole ba de

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji Lebo Kofi eran elede bofa Epo ati eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

AJE Ewe saworopepe ao lo tio Kunna dada pelu iyere ao fi se eran Elede ti gesi 16 je lepo niyo Ao te iyere osun ni obara oturupon Ao se adura si dada Ao je gbogbo re. MEDICINE

Videos

Watch Obara Oturupon teachings on our channel.

Explore Ifa

Obara Oturupon is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Ogbe, Obara Oyeku, Obara Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Obara Oturupon Odu.