O
Odi Meji represents a time of overcoming great challenges with strength and resilience.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Odinmeji
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Odinmejeji loto lowa re joko adifafun Onibode ajegbere mogun Igba ti momi ojusogbere ire gbobgo Ebo ni won ni kose O si gbebo orubo
Nje ire gbobgo poro ni bode
Ni bode ni ile aje
Ore gbogbo poro ni bode
Ni bode ni le iregbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii orubo nitori ire gbogbo pe oju ire gbogboni pon eleyin ebo ire gbogbo ni koru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye Meji
Akuko kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Itaruku lawo itaruku
Itaruku lawo itaruku
Adifafun igba
Ti n sawo rode oyo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa nipe ki eleyin orubo pe ire fun lopo lopo awon gbogbo ohun fi eleyin bafe ko mon se komo bere lowo ifa ki ire olede fun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbado
Ewa
Isu
Oruko kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Asahunkulu monkulu moyin baba
Adifa fun idin ati igogo
Ni ojo tiwon lole kan rile omo ni bibi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifani ohun pe ire omo fun eleyin pe oju omo ni pon eleyii pe koru boo mo kio si monk o egbin kole ba biwon.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aran elede odidi kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki deyin orubo emi re pee mi re yio gbe ebo ni koge daradara.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aran Agbo kan
Epo
Eku
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao foju agbado ati okababa ati ewa ati ewe ato ao wa jo po ao wa won fi fo eko mun tabi ka fi oyin lo.
ISEGUN
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe imon ewe apada ewe dandan ao gun meteta po mon ose dudu ao mon fi we fun ojo mesan tobaje okunrin tobaje obinrin ojo meje ni yio fi we.
Explore Ifa
Odi Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Odinmeji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Odi Ogbe,Odi Oyeku,Odi Iwori,Odi Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Odi Meji Odu.
