O
This Odu signifies the importance of overcoming obstacles through wisdom and perseverance.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Idingbe
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Gindanginda lalulu ogindigbo
Adifafu oju abufu aye ti won sayaolofinAwon lose fafunOlofinNijo ti won ni korubo
Ki oju ati aye omo n banun
O si gbebo nibe
Orubo
Nje awa roju o asunraye
ari ohun to muni awayo
Ao toju sigidi alamon ao wa toju eyin sin Horo ao wa egusin itoro yin ao wa fi se eyin si lenu ao wa mu irun ara oruko ao wa fun si lori ao wa pa eran oruko le lori ao wa logbe sidi esu fun ojo mesan ti o ba di ojo kesan ao wa bi ifa bi abati se boya arin monle ni o boya alo so sinu igbo ni o.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyi orubo ola kio si rubo ki ore omo banu tori ore kan lofe nu yin ebo ni kose ki ore naa omo banu kio lofi akuko adire kan bo esu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Epo
Eko
Obi.
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ogunijimogbe awo ni
Adifa fun Oruminla
Baba da idingbe
Won ni ikude
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa sope ohun pere laiku fu eleyin
Ki eleyin orubo eemi re ki won o si se fabe fun ki si fi oru Ko rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Sigidi
Epo
Eko
Obi.
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Musa awo awusa
Awa awo ode ejigbo
Ogere ti mogbe awo won lode ido
Adifa fun won lode ido
Nijo aye won lekoko
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ohun pe ire isegun fun eleyi
pe ikan eleyin ledie ebo ni kose
kosi sora fu ikan ewo idile won
ki osi mu fi ikan eleje runbo
ti ifa bamu ebo sibe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo owo
Epo,
Eko
Obi
-452120-199390
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Idingbere ariunaa ko
Adifa fun Lajubola
Ti yio soko arugbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ape ohun pe ire aya fu eleyin pe oju aya nipon eleyin fun gbo ti obe fefe aya eni toju lo niko fe kole ba tete bi mu kio si lobo ifa ape ilu eku eja abidie
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abode kan
Epo
Eko
Obi.
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju ewe anu ao wa lopo mon ata ijosin ao wa fi se eyin adire merin je lepo niyo eni naa yio je obe yi pelu adura gbogbo ohun ti o ba fe.
Explore Ifa
Odi Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Idingbe. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Odi Meji,Odi Oyeku,Odi Iwori,Odi Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Odi Ogbe Odu.
