O
This Odu represents the need for cleansing and renewal.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Idin se
Irele se
Igi ogba se
Keni o yomisi
AdifafunOrunmilaNijo ti baba dako die lagbala
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi orubo omo ifa ati okunrin ati obinrin ni won o jo rubo naa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie meta
Pepeye funfun meji
Akuko adie meji
Eku
Eja
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Idin sese
Awo eja lo sefa fun eja
Nijo ti n gbogun lo ilodo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki elehun o mon gbokanle oogunetutuni ki elelhun ogbokanle ki o mon yan koyan oogun laelae
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Okete
Esun isu
Akuko adie meta
Atare meta
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Idin se
Irele se
Igin ogbase keni o yomi si
Adifafun asinwin ile oba
Abu foba panpa
Won ni ki won o rubo
Ki won o le baa lase lenu
Won si gbebo nibe o won rubo
Nje, osese imoko are
Iti ifa bawi ni yoo se
Moko are
Osese moko are
Iti oba bami ni yio se
Moko are
Osese o moko are
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe won ofi elelyii seolorinibikan ifa pe kofi pelepele se ki ipo naa le badi tie ki won le mon ponle nibi gbogbo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo igbin
Aso funfun
Akuko adie meji
Agbebo adie meji
Epo
Eko
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Idin se
Irele se
Adifafun ase bagebage
Nijo ti n momi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa peki elelyii o rubo ntori gbogbo nkan bi ajogun buruku tui o fem on sele si ki o mon fi ebo se awada kotete rubona
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
oruko kan lEBO
agbebo adie meji
eku ati eja fun ifa
obi ati oti
epo ati eko
ewe abirikolo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
ewe abirikolo
ewe alupaide
ewe swegun sete
odindi atare meta
ao jo papo ao le ti okunna dada
ao te ni odu ifa (osedi)
Explore Ifa
Odi Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Odi Meji,Odi Ogbe,Odi Oyeku,Odi Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Odi Ose Odu.
