Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Odi Otura

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for balance and harmony.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/odi-otura
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Idin atago keyin aparo Ohun ti oju bawa lojuri Adifafun baba adabaje kun Baba adaba jeja Baba adaba ni kan kinle baba re

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifayi ifani ore re kan yi ko year fun ore naa ko ma ba fa le aye lo. Ifa ni awon kan nso lati mun. Ifa ni ipase orere ni won fegba mun korubo ko si yera fun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oti gbenu aho Oti jawon logun Goodagbo gbeju Yolololo Adifafun esinja Abufu esikin Igbati won momi oju sogbere ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifayi. Ifa ni korubo ija araye ko si rubo ki owo o leje fun asore kan nbe mola mola lori ko firu ebo ni o.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Aso mola mola Opolopo owo Abo adie
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Idin atago keyin aparo Ohun ti ojuwa lojuri Adifafun nini eru orisa Abufun alini eru orisa Igbati won momi oju sogbere ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifayi ko rubo iyii, ifa ni ibi kan leleyi nlo korubo ko le ba gba yi nibe korubo isegun ota

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko Eye Etu IgbinEyeleOpolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Iwo ni idaji ara Adifafun idin Nijo tololedare olale nilealara

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifayi ki eleyi o rubo ifani oun ti eleyi da si o tidamundamun loree o ti was u ifani korubo ki ara o le baro

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

EyeleAgbeboadie Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe olajuwere ori okete ao gun pomo ose ao fi iyerosowu te odure ni otua do ao pe ifa si ao po mo ose ao ma fiwe larolaro

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Opolopo ekolo abo adie funfun kana o pa adie yi si orifa gbogbo iye re sinu odo ao wa la inu adie yi ao ko gbogbo unkan inure sinu odoo epo obo ao ko si ekoloyi ao ko sinu odoo ao gun gbogbo re pomo ose dudu ose pupa ose funfun ao ko ose yi sinu ikefunfun ao mo we ao wa fi adie yi pa ese fun awon iya mi ao wa bere ibi ti won o ti gba ao wag be lo fun won.

Videos

Watch Odi Otura teachings on our channel.

Explore Ifa

Odi Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Odi Meji,Odi Ogbe,Odi Oyeku,Odi Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Odi Otura Odu.