Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Okanran Obara

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the balance between wisdom and action.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/okanran-obara
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okiti baba nipeku opopo Adifafun oloba abedi Omo ariyinkunni bomo lenu Igba timomi oju sogbere Ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa nip e ire gbogbo fun elelyi pe ki elelyi omu oju to awon irunmonle daradara kio si lobo ifa ati orisa pelu eku eja abodie igbin pupo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku Eja Abodie Igbin pupo Epo eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Okinti baba ni peku opopo Adifafun aso tigbogin ropin atari

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oppe ire isegun fun eleyi ki elelyi orubo isegun kolo bo esu ori re pelu eran oruko kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan Epo Eko Obi Oti
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okanran bababa Adifafun bata nijo tilolegba Roro obinrinsango

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pe oun pere gbogbo fun elelyi pe oun sip e ire aya fun elelyi pe ki elelyi olo bosangopelu agbo ati a mon la gbegirin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran agbo kan Orogbo Amonla Epo eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Okanran bababa Adiafun ori ori tode orun bowale aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire gbogbo fun elelyi ki Eleyi olobo orire daradara Pelu eye etu kio si fieyelerubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kanEyelekan Epo Eko obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe gboro ao toju ewe omini ewe aje ewe sajeje ao wa lagbogbo re po ao wa fi se abo adire toti pamon ri kaje lepo niyo ao wa se adure si ao wa je obe naa ni ori ifa ni ao ti je oba naa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju awo bata tabi ida oju bata ao wa gun mon ose dudud eni naa yio ma fi we un ojo mesan

Videos

Watch Okanran Obara teachings on our channel.

Explore Ifa

Okanran Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Okanran Meji,Okanran Ogbe,Okanran Oyeku,Okanran Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Okanran Obara Odu.