O
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Okanran won won
Awo lose fafu aja
Eyin tiyio mon raru atosi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki elelyi orubo aru ki aru ti koni gboogunomon bamon se kio rubo kio bo ifa pelu oruko kan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Kapebirin koto kamule
Kapebinrin koto kamule
Kamule kamon darawa
Adifafun olokanran
Nijo ti lole dari eku anaa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire isegun fun elelyi ki elelyi osi maa so otoo dara dara kio si lobo ile pelu eku eja orogbo obi atare pepeye ekuru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Pepeye kan
Orogbo meta
Obi meta
Atare meta
Ekuru funfun
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Okanran owonrinOnilelo lare
Ajoji omo se le omo
Omile aon ate jeje
Adifafun aye nijo tilole rale leru
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa nip e ire gbogbo fun eleyi ki eleyi orubo kio si mon ta oun kan inin re tio ba si fe tahun ko bere won kio mon ba seta orire re mon oun ti o ba ta kio fi akuko adire meta rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meta
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa so pe ire okere fun eleyi
pe ibikan ni eleyi loyi ebo
ni ki eleyi ose kio si lobo iofa
pelu ewure kan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao toju ewe isin pelu ewe iya ao wa lopo ao wa fi se edo monlu je lepo ni yo ao wa se adura si dara dara ao wa je obe naa ao wa lori ikoko taba fi se be na man le akogbodo lomon ki obe naa ole si se daradara
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju ori eku eye keyin sorun ao wa gun mon ose dudu ao wa po mon imin ojo ao wa mon fi we laro laro
Explore Ifa
Okanran Owonrin is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Okanran Meji,Okanran Ogbe,Okanran Oyeku,Okanran Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Okanran Owonrin Odu.
