O
This Odu signifies transformation and the importance of embracing change.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Yangin abori kugun
AdifafunolokunEyi tomore yenkun
Ti omo re yanku loju aye re
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pe oun pe ire aiku fun eleyi ki eleyi ofi opo lopo isu kun ebo ru pelu akuko adire meji rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meji
Opolopo isuko
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Koko rere todara niba nigbe inu ile
Eyin ti koseni awo siu eranko
Adifafun osan abu foro
Nijo tibaba momi
Ojusogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire omo fun eleyi ki lelyi ofin opolopo osan ati oro rubo kio si fi eku eja abodie rubo kio fib o ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Abodie
Osan
Oro
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Tekuti lawo omode
Tekata lawo alare
Ikakan soso loku kodeji oye
Beni kole deji oye
Adifafun sebo koru omo
Igba ti n momi oju sogbere ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa nipe oun pe ire gbogbo fun eleyi ki eleyi olo fie ran elede bo ifa ki ara ole bade
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran elede kan
Epo
Eko
Obi
Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Agbon nije nibi are are
Ope agunka logarun gase
Ope agunkan nidun loru
Oja gbo lo
Adifafun olu nijo tilolejola ifa
Lode isa laye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere gbogbo fun elelyi ki elelyi orubo kio si lobo ifa pelu eran ewure kan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao toju ewe akika die
ao fin se eyin adire ibile
meta pelu ori ni epo re
ao fi iyo si ao wa se
adura si ao wa je ni ale
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao toju aparin isu ako ao wa fi odidi atare kan kun ati ewe apada ao wa jo papo ao wa fi si gbere larija eyin toba ku ao wa po mon ose dudu ao wa mon fi we larolaro
Explore Ifa
Okanran Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Okanran Meji,Okanran Ogbe,Okanran Iwori,Okanran Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Okanran Oyeku Odu.
