O
This Odu signifies the importance of patience and persistence.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Olobara reterete
Babalawo oka
Adifafun oka alawo bobo
Ekun omo nisun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o gbo oro ti
Awon babalawo ba so
Ki o si fi aso re
Alawo orisirisi ko firubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aso alaranbara
Akuko meji
Epo
Eko
Ori oka lebo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Obara reterete
Babalawo omi
Adifafun omi
Igba ti ntori bo wa saye
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin pupoEyelemeji
Epo ati eko
Agbebo adie
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Peegun loruko tape oka
Peregun loruko tape ere
Olobara beekube loruko tape igbin
Adifafun alaso dudu oke ape
Igbati nfomi oja sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ki elelyi korubo
Ntori omo ki o mon
Badi eni ti ko ni ni
Omo laye mon
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie meji
Pelu igbin merin
Akuko adie kan
Fun ebo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Koni igi nla ko fi ewe parunparun
Kun ko wa gun papo mon imi ojo kosi
Eru pe ifa re obararete
Ki o mo se adura si ki o to mon fi para ao da sinu ipara ti o ba loorun
Explore Ifa
Obara Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Obara Meji,Obara Ogbe,Obara Oyeku,Obara Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Obara Irete Odu.
