O
Obara Meji indicates a period of dynamic action and progress. It suggests significant movement and achievement.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Pelebe idin awodin lawo laoke
Ka to mo ero agogo niriro
Adifa funolofinEyi ti yio mon da obara meji rogba rogba oloju opon ifa Ebo ni won ni ko se
O si gbebo ni be orubo
Nje ifa ni n o laje molaje
Ebora alase obara meji
Abise wara ifa ni n o nire gbogbo
Moni re gbogbo
Ebora alase obara meji abise wara wara.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire gbogbo ni ohun ri fun eleyin ebo ire gbogbo ni ko mo se.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abo adire kan
Epo
Eko
obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Orore ni kolagba ninu
Gbogbo eye oko loda weese wese
Adifa fun eji obara
Eyi ti dala ji ki lola
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyin orubo ape sin pe eleyinkorieni pesi ebo kose kio le bari eni pe sin
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Onibara
Olabara
Eyin omo peye bara bara kii kate
Adifa fun orofo
Nijo ti lo leje ayaba eye larin igbe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyin orubo ajinde ki osi rubo oye pe won yio peeleyin si oye kan ki o mo sope ohun ope tori oye naa yio sodieni ninla.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meta
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Kesekese leri
Kasakasa n bo leyin baba kesekese
Adifa fun agbigbo niwon ran
Ti so logun eba loro
Adi fa funorunmilaNi jo ti agbigbo fe gbe eru buruku lebaba lori
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyinorubo emi re pe awon kan ni wagbe ohun burukub o wa kawon le koru bo ki elerun ole gberu re kia kia kiosi lofin emi re bo ifa fa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
A o toju ewe aki ka ti je ewe agbayun ao wa gun mon ose dudu eni naa yio mon fi we.
ISEGUN
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
A o mun ewe alupaida mesan to baje okunrintoba je obinrin mmeje ao wa mu eyo atare meje tabi mesan ao wa fi si gbere mesan fun okunrin meji fun obinrin.
Explore Ifa
Obara Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Obara Ogbe,Obara Oyeku,Obara Iwori,Obara Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Obara Meji Odu.
