Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Obara Ofun

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of wisdom and insight.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/obara-ofun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Obara fun nigin nigin Adifafun ope eluju Ti ogarun gase ntori ire

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki orubo ntori ore Ti nbo fun ki ore naa ba Sonu mon lowo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meji Pelueyelemeji Pelu epo ati eko Pelu obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Olobara funfun ninini Adifafun bara ti n lo Oko ailero odun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi omon se Ai gboro si nkan ti Awon awo ba so fun won Ki o mun oro nani okun kundun Ifa pere fun eni to da ifayi ifa ni ola awon ala ti o da ifa si ni ibi kan nbe ninu ile re to bo ibe lawon ajogun ngba wole ko ole ati simeti kopo papo mo arawon ko fidi ibi ko fi ewe alupaida ati ewe agbesi kun ebo ru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji Akuko adie mejiEyelemeji Epo ati ekoEyeleAkuko adie Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Obara funfun ringinringin Adifafun eku ti n lo le Ji obinrin ebiti

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o mon Ja eni kejire lole To ba danwo iku ni ere re ifa pere fun eni to da ifa ni ko rubo ki ire oba le ya ile re ki ire to be ko ma ba ja de ko fi akara elepo bo ifa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meta Eyin pepeye mejo Eko eda meji Epo ati eko Akara elepoEyeleAkuko adire Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Obara funfun ringring AdifafunorunmilaBaba n lole fun ntori aje

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi Olobo aje koleri Aje jeun ki aje mon Ba won eleyi ifa pere fun eni toda ogunda bede ifa ni awon ota po fun korubo kole ba segun ko fi irere meji ni o je bayen

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyelefunfun fun aje Agbebo adie meji Fun ebo Akuko adie fun Isegun Epo ati eko pelu obi. Irere mejiEyeleOpolopo owo Akuko adie

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ogomon ope ewe emile Iyere ao lopapo Afise igbin meji lepo niyo je Ao te iyereosunni obara ofun Ao se adura si dada Ao je gbogbo re pata Gbongbo oju ona to ta koja aogo ao yo larin ao lopo mo iyere ao fi se igbin meji lodidi lepo niyio

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao bu die lara esu tin gbebo ao lo tiyo kunna dada ao ma fi epo pupa la ni ale tia ba ti fe sun

Videos

Watch Obara Ofun teachings on our channel.

Explore Ifa

Obara Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Obara Meji,Obara Ogbe,Obara Oyeku,Obara Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Obara Ofun Odu.