Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Obara Ogbe

Obara Ogbe also known as Obara Bogbe
Aliases:Obara Bogbe
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of wisdom and foresight in overcoming challenges.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/obara-ogbe
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Obara Bogbe

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

ESE IKINNI Olobara bobo bob Adifafun ogongo Ti n sa wo lo si Isale akitan tin lola Bawon gbofa ola tontomo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elleyi orubo tori oun tije aseyori Ki osi rubo ntori omo Ki nkan ti oba so fun ifa Ki ole mon rine Ki o si rubo ola pelu omo nbe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyelefunfun merin Agbebo adie toti pamori merin Epo ati Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Opon ifa aboju telu AdifafunorunmilaBaba obi tifase lomo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki elleyi nkanti Ifa ba sofun toripe gbogbo Nkan ti ifa ba so fun pata Niyio se

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meji Pelu epo Eko Kosi fi agbebo adie kan Bo ifa re ki ifale gbo Gbogbo nkan ti obasa opata
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Olobara boboo Babalawo ekolo Adifafun ekoklo Igbati asunkun omo Lo si isale abata

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi otete rubo Ntori omo Ifa sini ibi ti elleyi otifi Olomo Ifa pe ibi egbin ati Iwosi ni yio ti olomo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebio adie meji Pelueyelemeji Epo ati eko Lebo re.
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Iku oyoArunoyo Adifafun won ni idomun Niniti won ti ntan ina roro Le iku,arun, oto gbogbo ajogun lo ISEGUN Eni ti o fi sun ati idoti inu ile re Yio fi gun ose pelu eeru alamon Yo te ifa obaragbogbe yio se adure si dada Yio mon fi we ni ojojumon

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki elleyi Otapa yi po ile kosi gbon Gbogbo lere jade patapata Ntori gbogbo ajogun buruku

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meji Pelu pepeye meji Epo ati Eko

Videos

Watch Obara Ogbe teachings on our channel.

Explore Ifa

Obara Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Obara Bogbe. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include:Obara Meji,Obara Oyeku,Obara Iwori,Obara Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Obara Ogbe Odu.