Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Odi Owonrin

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of adaptability and flexibility.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/odi-owonrin
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Idin arinrinmarin Idin arinrinmarin Adifafun idin Idin sawo rode Oyo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni awon ota wa fun eleyii pe won si n wo o wioe ko ni di odun ti n bo, oe ebo ni ko ru.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Isu apepeEyelekan Epo Eko Agado Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Idin gaga gungun Idin gigi roro Adifafun ori nje Ti n sunkun pe ohun oni enikan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o boa wonegbe, pe awonegbere ni won yoo ba segun gbogbo ota ti o ni.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Gbogbo ohun tenu nje Epa, ireke, aaadun, oyin Ogede Ekuru, eyin Epo, eko Agbado, owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ori sawo titi ori gbade Ori sawo titi ogba ejigbara leke Idin sawo titi ogba monsajin aso oba Ti ko naa yanranyanranOrunmilasawo titi logba ebutu isu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere aje fun eleyii, ifa ni ebo ni ki eleyii o ru, ko si dimo oun ifa daa daa, pe oun ifa ni ki eleyii o dimo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Epo Eko Agbado Owo Obi meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Kukute agbon ni kosorun Adifafun baba mosubu yege Erin mi Igba ti momi oju sogbere ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere ire aje fun eleyii, ifa ni ebo ni ki eleyii o se, ki o sib o orisa aje daa daa ki ire aje o le baa sunbo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyelemeji Epo Eko Agbado Oti Owo Ekuru funfun Obi

Videos

Watch Odi Owonrin teachings on our channel.

Explore Ifa

Odi Owonrin is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Odi Meji,Odi Ogbe,Odi Oyeku,Odi Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Odi Owonrin Odu.