O
This Odu signifies the importance of adaptability and flexibility.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Idin arinrinmarin
Idin arinrinmarin
Adifafun idin
Idin sawo rode Oyo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni awon ota wa fun eleyii pe won si n wo o wioe ko ni di odun ti n bo, oe ebo ni ko ru.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Isu apepeEyelekan
Epo
Eko
Agado
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Idin gaga gungun
Idin gigi roro
Adifafun ori nje
Ti n sunkun pe ohun oni enikan
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Gbogbo ohun tenu nje
Epa, ireke, aaadun, oyin
Ogede
Ekuru, eyin
Epo, eko
Agbado, owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ori sawo titi ori gbade
Ori sawo titi ogba ejigbara leke
Idin sawo titi ogba monsajin aso oba
Ti ko naa yanranyanranOrunmilasawo titi logba ebutu isu
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere aje fun eleyii, ifa ni ebo ni ki eleyii o ru, ko si dimo oun ifa daa daa, pe oun ifa ni ki eleyii o dimo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Epo
Eko
Agbado
Owo
Obi meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Kukute agbon ni kosorun
Adifafun baba mosubu yege
Erin mi
Igba ti momi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere ire aje fun eleyii, ifa ni ebo ni ki eleyii o se, ki o sib o orisa aje daa daa ki ire aje o le baa sunbo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemeji
Epo
Eko
Agbado
Oti
Owo
Ekuru funfun
Obi
Explore Ifa
Odi Owonrin is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Odi Meji,Odi Ogbe,Odi Oyeku,Odi Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Odi Owonrin Odu.
