Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Oturupon Ika

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the power of transformation and the importance of strategic planning.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/oturupon-ika
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oturupon ka Oturuopon ko Awo ori lose fafun ori Ori tode orubo waye ao toju ewe iyeye pelu owo eyo iyere ao wa lopo ao wa fi se eran okete odidi kan lepo niyo ao wa ko obe yin si ori ifa ti obajinaa too ao wa se adurasi ao wa je obe naa gbogbo oun ti abele je ni nu obe yin ao ko si ibikan ao wa mu ewe mejejeji yin ao wa gun papo ao wa po mon ose dudu ao wa on fi we laro laro

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire ola fun elelyi Ki elelyi orubo ola kio lobo ori Re pelu eye etu kan kio si lo fi eye eku kan bo fa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu meji Epo Eko obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oturupon kan pon ko Adifafun orunmila ni jo ti Baba momi oju sogbere aje

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi ki elleyi orubo ki o si lobo ifa pelu pepeye kio si fi oruko rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan Pepeye kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oturupon ka Oturupon ka Pon ko ponko majalawa Adifafun omi subu laje omo Oni gbobu aran Igba ti momi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pere omo fun elelyi pe oju omo nip on elelyi korubo pelu eran ewure kan ati ye imu fun ifa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Oturupon kan pon ko Ponkoponko ponran ete Adifafun egbe aye Abufun torun Igba ti won tode orun bowaye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pere ire ola fun eleyi ki eleyi olo bo egbe orun re pelu gogbo oun tenu je kio si fi akuko adire meta rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meta Gbogbo oun ti enuja Epo Eko Obi

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju ewe apada ao toju ewe labelabe ao wa po mon ose dud ao wa lo bin pe agbde ao wa ko ao po mon ose naa ao wa mon fi ose naa we.

Videos

Watch Oturupon Ika teachings on our channel.

Explore Ifa

Oturupon Ika is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oturupon Ika Odu.