O
This Odu highlights the need for patience and perseverance in achieving success.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Tete oniru
Awo ile oluganbe
Losefafun oluganbe
Igbati mon oju sogbere iregbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire gbogbo fun elleyi
Ki eleyi olobo ifa ni eku eja
Abo adire kio si fi akuko rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abo adire kan
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Oturuupon tete awo toto
Awo todido tododo
Adifafun odod nijo ti lolegbayin
Ninu ewe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire iyin fun elelyi
ki elelyi olo fi eye etu bo orire
ki olo badi eni nila kio si fi eye etu kan naa rubo fesu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Epo
Eko
Obi
Oti
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Oturupon tete awo tooto
Oturupon tete awo todoto tododo
Adifafun awoko nikuyugba
Tise omo oloro kan atijo
Igba fimomi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire gbogbo fun elleyi
ki eleyi orubo kio si fi opolopo
ede bo ori afi ifare pelu efo
tete ati abo adire
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abo adire kan
Opolopo ede pupa
Opolopo efo tete
Obi
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Oturupon tewure
Adifafun tete ni jo ti won ni korubo
Ko mon bate lawujo ebe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki elelyi orubo iyin pe
awonm kan ni won fete elelyi kio
rubo kio fi pepeye rubo kio si fi irere bo orire
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye kan
Irere kan
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ESE KINI
Ao toju ewe awoyoyo ao toju
ewe iyabo ao toju iyere ao lo metata po ao fi se opolopo ede lwepo ni yo
ao wa se adurasi ao wa ye obe naa ni ori ifa
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju ori irere taba fib o ori yin
ao toju ori pepeye ao toju ewe
segun sete ao wa jo meteta
po ao wa po mon ose dundun
ao wa mon fi we laro laro
Explore Ifa
Oturupon Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Irete Odu.
