O
This Odu emphasizes the importance of strategic planning and thoughtful decision-making.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Tuwetuwe ni ru gbo
Emi omo eni toni ki tuwa
Adifafun ofafa igba ti niragun ota
Ao toju ewe anu ati ewe saworo pepep ao wa fi se eyele funfun kan ni epo ni yo ao wag be sori oopa aso funfun kana o wa se adura si ao wa je obe ni ni owuro ojo keji ao wa lofi aso funfun yin si ori orisala
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire isegun fun eleyi
ki elelyin olo fie ran ofafa rubo pelu akuko adire meta
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meta
Eran ofafa
Epo
Eko
Obi
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Botewure kotewure
Bonaagbaja onaagbaja
Adifafun abure tise eru ikoku olofin
Igba ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni ki elelyi oru bo isegun
pea won kan ni won gbogun ti
eleyi kio lo fi abere kun ebo
re pe lu eran oruko kan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Opolopo abere
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Eyele kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Tuwatuwa in mogbo
Emi omeni toni ki tuwa
Adifafun orunmila
Baba lole bawon eleyi mule
Lagbala
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pere isegun fun eleyi
ki eeleyi osi lofi ewure bo ifa
ko si fi gbogbo hinkan
inu ewure yi pese fun awon iyami
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju iru ara ewure taba fib o
Ifa pelu ewe oriji ao wa po
mon ose dudu ao wawe ose naa bi ojo bepo firi ao wa be awon agba lagba pe
ni epo pupa igokan lafi pese fun wa lale.
Explore Ifa
Oturupon Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Otura Odu.
