O
This Odu emphasizes the importance of balance and harmony in life's journey.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Oturupon funfun ninini
Adifafun aje
Omo olopo oni
Omo abani tunle aye eni se
Igba ti n tode orun bo waye
ao toju owu alatakun ti otira yileka
ao wa op mon ose dudu ao w ate iyere osu ni odu ifa
oturupa fun ao wa se adurasi ao wa po mon ose yi ao wa mon fi we larolaro
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa nipe oun pe ire aje fun
elelyi ka elelyi orubo ko le ba
ri aye jenu kio lo fieyelefunfun bo aje ati ekuru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelefunfun meji
Ekuru
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Erin ke
Oyin sese
Adifafun kowe
Ni jo ti n lo lee pabi lafin
Okofurupo
Adifafun alagbamun
Ti won ni o ruboarunori
Gegenge lawo gengenge gee
Geengee lawo geegeengee
Ka tidi ogan bomi
Ka tidi okoo bomi
Adifafun aridegbe
Omo oni ju mun nanki
Omo odo idea bon e la komun rele
Ijumun ile baba re oye wo ni mun lo ni dere apa.
Otua ganga
Iwori naa gangan
Kokunrin ganga mo dido bale fo kunrin ganga mo Adifafun liase
Ti se ayaagbonniregunIgba ti n momi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire gbogbo fun
eleyi ki elelyi olo fi opolopo
obi abata bo if pe lu agbebo adire kan
Ifa pere fun eni toda ifayi ifani ki eleyi oruboarunori ki o si ruboarunara ko fi fila pupa kun ebo ru.
Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni oju omo pon enikan legbe e;eyi ifa ni korubo ko sib oosunati ifa leku leja labo adie yo fi adie agada boo sun.
Ifa pere fun eni toda ifayi ifani ki eleyi o fun ra si iyawo re nipa irinkurin ifani iyawo eleyi oun rin awon irin ti o da oun ni ko je ki o ni oyun ifa ni iyawo eleyi gba inkan lowo okunrin miran o wa mun wole inkan to gba yen lo fa ti o fi loyun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo obi abata
Agbebo adire kan
Epo
Eko
Obi
Akuko adie
Opolopo owo
Agbebo adie
Eja
EkuEyeleOpolopo owo.
Agbebo adie
Oruko
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Oturugbowu lebe lebe
lomulo oju oru loleran
Adifafun alatakun
Eyi ti yoo mon se oun gbogbo bidan bidan
Ori koku awo won lodeegbaSunbola awo won lode ijesa
Abusundaji ni sawo won lekoto iwerejeje
Adifafun ori
Ori nlo le ko fun ku
Otua buye
Oni a mori mobonu aso ni baba aja
AdifafunorunmilaBaba o da kengbe iye bori
Nitori iku
Okete wure
Adifafun won lode ibon
Igba ti won raye alaini ku
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire gbogbo fun eleyi ki elelyi olorubo kio si lofi ewure bo ifa ki o si fi otutu owu
kun ebo re
Ifa pere fun eni to da ifayi. If ape awon kan won sa inkan buruku si eleyi ifa ni ori re ni bele yin ti o je ki inkan ti won nsa ole ran kobo ori re ko fi konko bo ori ati obi, oti.
Ifa pere fun eni to da ifayi ifa ni oun pere aiku fun eleyi ko rubo iye ni won o fir u ebo yi o ki o po dada ki won o bu si eni naa lori dada
Ifa pere fun eni to da ifayi ifa ni ki eleyi o rubo ayo bi ki ajogun bi o ma ba wole to ifa ni oke kan wa niwaju ile awon eleyi ifani oke yen ni ko rubo si ifa ni ebo ti won ru yi ibi oke yen ni won o gbe lo ifa ni ki eleyi ko rubo nitori iku.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Otutu owu
Epo
Eko
Obi
Akuko adie
Konko lopolopo
Opolopo owo
Akuko adie
Opolopo owo
Oruko
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Oturugbowu lebelebe
Komu le oju oruloran
Adifafun araba pataki
Ti n be laarin ota
Ire taipejamoja
Adifafun alaba owo
Omo osungbedu
Igba ti n momi oju so gbere ire
Ori ko ku awo won lodeegbaSunbola awo won lode Ijesa
Abu sun daja ni sawo won ni kotewerenjeje
Adifafun omowunmi
Omo ataso gbomo lowo won
Igba ti n momi oju sogbere omo
Iteku asa
Adifafun otua
Tio fowo yepin
Ore ayanyanju
Ni mun won yan ore ekore
Ayanyanju
Ni mun won yan oore o dale
Adifafun akuko ti se ore kolokolo
Otua wo wo wo
Iwori naa wowo wo
Adifafun arugbo
Ti n loko yanrin
Otua ganga
Iwori naa ganga
Okunrin ganga ko mo dido bale fun okunrin ganga mo
AdifafunorunmilaBaba n sawo rode isan
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni pe oun pe ire isegun fun elleyi ki elelyi ofi odiid eran oruko kan kun EBO run ati opolopo otutu
Ifa pere fun eni toda ifayi, ifa ni gankan yi toju omo n pon ifani aso kan nbe ninu ile eleyi ito filo ifani ko fi rubo nitori omo tabi oun ati awon kan jo fera aso kana won yo kuno ri owo oun nikan lo lodara ifani ko firubo tori ko leba bimo.
Ifa pere fun eni to da ifa yii ifa ni ki eleyi o rubo if ape koma fi inu han ore ko ma ba pa ifa ni oore kan ni yi ti won jo feran ara won tiwon jo wa arawon ifa ni ore yi ma n beru re pelu in kan to n fi seagbaraif ape ore yo wa b ape ko se idiagbaranaa fun oun komo so o fee pa ni.
Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni ara koro eleyi ko rubo ifa ni eleyi o se ore fun enikan yow a fibu su ifa ni ko mo ba eni naa if ape oun loun ogbija eleyi kobere oun ti fa o gba ko si bo ifa dada.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Opolopo otutu owu
Owo pupo
Epo
Eko
Obi
Agbebo adie
Opolopo owo
Oruko
Opolopo owo
Agbebo adie
Eku
EjaEyeleAkuko adie
Opolopo owo.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe inabo a o lopo mo iru isebo ati iyere a o wa fi se eran elede ti a ge si merindinlogun (16) lepo niyo ti o ba tijinan a o koje ni gbigbon.
Ewe ina ewe esisi ewe arangba ewe oloyin a o lopomo iyere a o fi seeyelekan ti a ge si merindinlogun (16) leponiyo ti o ba jinna a o je.
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju ewe igin araba ati odidi atare kana o wa jo ti abajo tan ao wa fi si gbere larija ao wa la fi iyoku fo eko mu lori odu ti ati lo tele
Odo ewe peregun meta eru Alamo meta a o gun pomo ose a o ko ose yi sori okuta ako a o ma fiwe laro laro.
Koronfo eyin adie ibile ti o pa fun rare a o lo ti yo kunna a o wa pomo ose a o ma fiwe laro laro.
Explore Ifa
Oturupon Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Oturupon Meji,Oturupon Ogbe,Oturupon Oyeku,Oturupon Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Ofun Odu.
