Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Owonrin Ofun

Owonrin Ofun also known as Owonrin Wofun
Aliases:Owonrin Wofun
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of wisdom and insight.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/owonrin-ofun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Owonrin Wofun

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Owonrin wofun Wedo Babalawo Adifafun igbangba Nigba ti n torun bowa sile aye Adifafun Awo awo Igba ti n tode orun bo wa sile aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eleyii, ifa ni ki eleyii o rubo pe omo iya eleyii kan re e, ota re gidigidi ni, ki eleyii o rubo ko maa je pe yoo fe e paa.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igba olomori Awo olomori Akuko adie kan Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Owonrin wokun woku Adifafun oro Ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyii o rubo ko le baa segun nitori ota po fun eleyii.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko Kan Obi meji Oti Akuko adie kanEyelekan Epo Eko agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Owonrin worun wedo Adifafun Alabahun ajapa Ti n loko ai lero lodun Owonrin wokun wedo Adifafun Olunlawe Ti n rode orun bo wa sile aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire fun eleyii, pe ibikan ni eleyii n lo, pe yoo la bo nibe sugbon kogbo ikilo ti won ba n wi fun un. Ifa pere ola fun eleyii lati okere, pe korubo ki ire ola naa o le too lowo ni kia kia.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igba olomori Obe Epo Agbdo OwoEyelefunfun meji Obi merindinlogun Epo Eko Agbado

Videos

Watch Owonrin Ofun teachings on our channel.

Explore Ifa

Owonrin Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Owonrin Wofun. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include:Owonrin Meji,Owonrin Ogbe,Owonrin Oyeku,Owonrin Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Owonrin Ofun Odu.