Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Owonrin Oturupon

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of introspection and self-discovery.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/owonrin-oturupon
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Owonrin baje lese Ariwo yee, ariwo yee Adifafun Orunmila Baba n be laarin ota meta

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo pe eni ti eleyii n fi oro re lo naa ni ota re.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie kan Obi meji epo Akuko adie kan Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Awoka woka igbin Awoka woka ikarahun Adifafun Ikakara Ti won ni ko ni pe lodo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo pe ibi kan wa ti won fe lekuro ni n be korubo kii awon ota o maa baa le eleyii kuro nile

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ikarahun igbin Akuko adie meji Epo Eko Agbado Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ajenje adifafun Eeyan Ti n seru ipin loru

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eleyii pe ki o rubo, ko sib o ori re pe ori ola ni o yan lati ode orun, pe ko rubo orire yoo sile kun ola re fun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku meji Eja meji Eyele meji Epo Eko Agbado Opolopo owo Agbon meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Kokan sagba Isagba ni duuru Adifafun Orunmila Ire aje n lo lode okan kan o yale

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eleyii, ifa ni ebo ki ire eleyii o ma baa se koje re ni ko ru, ki ire aje o le yaw a fun un.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan Abo adie kan Obi merindinlogun Epo Eko Agbado Opolopo owo

Videos

Watch Owonrin Oturupon teachings on our channel.

Explore Ifa

Owonrin Oturupon is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Meji, Owonrin Ogbe, Owonrin Oyeku, Owonrin Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Owonrin Oturupon Odu.