O
This Odu emphasizes the importance of resilience and strength.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Owonrin pakan lakan
Adifafun Sango
Ti n torun bow a sile aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo isegun, pe laarin ota ni eleyii wa, pe isegun o si de fun un.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meji
Orogbo meji
Epo
Eko
Agbado
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Owonrin wan kankan
Arami le gbaa
Adifafun Aase gbara gada
Igba ti n be laarin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo ko le baa ni isegun ninu ile, pe ota po fun eleyii, pe korubo ko le ba a nisegun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie kan
Eyele kan
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ajalu booboo
Adifafun Eja
Tii somo onibu iragbiji
Igba ti n fomi oju se irahun ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni keleyii o rubo, pe ire aje n bo feleyii lati okere, pe ebo ni ko ru, ki ire naa o le tete tee lowo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu kan
Obi merindinlogun
Epo
Eko
Opolopo agbado
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Owonrin pakan lakan
Babalawo eegun
Adifafun Eegun
Adifafun Orisa
Adifafun Orunmila
Igba ti won n tode orun bowa sile aye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni awon ore meta ni eleyii, pe ki won o rubo ki aje o le yale wa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu kan
Abo adie kan
Eyele kan
Epo pupa
Eko
Agbado
Opolopo owo
Explore Ifa
Owonrin Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Meji, Owonrin Ogbe, Owonrin Oyeku, Owonrin Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Owonrin Okanran Odu.
