O
This Odu highlights the need for balance and harmony.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Odu gbiri ikoko man yinso
Adifafun Oba ti lo lee daja
Adifafun Alabahun
Ti yoo maa lo lee tuja oba
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire aseyori ati isegun fun eleyiii lori enikan ti n bakan re je, ifa pe ebo ki o le ba a segun eni naa ni ko ru.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aworan meji
Alabahun meji
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Owonrin otua awo oninja
Okiti baba awo iredo
Adifafun toro minin
Omo ajate sun
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Owonrin otua awo oninja
Okiti baba awo iredo
Adifafun toro minin
Nijo ti n sunkun atila sururu
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Owonrin otua awo oninja
Okiti baba awo iredo
Adifafun toro minin
Omo ajate sun
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, toromininde
Omo ajatesun nin
Owo loosala wadenin apesin
Owonrin otua awo oninja
Okiti baba awo iredo
Adifafun toro minin
Nijo ti n sunkun atila sururu
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
E wa bani bola peregede
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere ola gidi gidi fun eleyii sugbon pe ebo ni ko ru, ko sib o oosa ire ola fun un, pe ola yoo je fun un.
Ifa pere aje fun eleyii, ifa ni oju aje n pon eleyii, pe ebo ni ko ru, pe yoo ri ire.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin mejo
Obi meji
Abo adie kan
Epo
Eko
Agbado
Owo
Eye etu kan
Eyele meji
Epo
Eko
Agbado
Owo
Explore Ifa
Owonrin Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Meji, Owonrin Ogbe, Owonrin Oyeku, Owonrin Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Owonrin Otura Odu.
