O
This Odu signifies the power of patience and strategic planning in achieving success.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ogunda roro
Irosun naa roro
Adifafun alari oun ododo
Won raye alainiti
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ika loun pere omo fun eleyi korubo kolebabimo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku eja abodie
Eyele
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ki lefi n sebo ogunda rosun ti n fi n fin
Won le ku ni abajo
Ti n firi kurukuru
Ki le fin seboogunda rosun
Ti n fi n fi won ni eja ni won
Abajo tin firi jaaja
Ki le fin seboogunda rosun
Ti n fi fin won ni eye ni
Won ni abajo tin fi riyeye
Kile fin seboogunda rosun
Tin fi fin won ni eran ni won ni
Abajo ti n fi n ri ranhun ranhun
Nje, orunmila mojewo
Obunda soromi mopo elejelu
Omo erin tin fan kikan
Omo erin tin fan gburugbaralalo
Won ni kin won fi sebo ogunda ti fi n fin Orunmila ni igbin ni
Nje igbin mi de molero akoko
Pero simi lori pero simi lorun
Esure abita rugudu
Ata tokunni tepa
Epa lotatan lofiibi jannanjannan gbadi
Adifafun memun ko riwa
Tii se are mogun
Igba ti n momi oju sogbere aje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa sope kin won o mo fi oro kun ogun yan ra won je ifa ni eleyi ko fi aso kun ebo rupelu fila to baje obinrin ni yoo fi ewure pelu gele ebo ru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Aso
Fila
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ogunda rosun
Gbaran gasa
Adifafun ile tii se oko lala
Okunsu nanre nanra
Osa su legbe legbe
Alasan rasan ala san n rasan
Agbagba imole ni o gbeyin oro
Wonripe kosun hin mo
Adifafun isese
Tise olori oro laye abuase se
Tii se olori oro lalade orun
Nje baba eni Asese
Iya eni Asese
Eni ori eni asese eni ni
Ikin eni asese eni ni
Olorun oba asese eni ni
Asese laabo nibe kato bo ebora
Asese ni baba etutu.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa loun pere fun eni to da ifayi korubo ifa ni arin ota eleyi wa ifa ni awon ota repo sugbon oun ni yoo segun kofi oka ati ada ku eba
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo owo
Oko
Ada
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ogunda leji irosun lote
Adifafun olomo
Ti o sowo sowo ti ara ilere nikoni pe
Pengele mole hun se keke ke mole reru Iteledi eni lawo bo ti laro loju si
Ewawo aso mi toko nan yanran yanra biaso oba
Adifafun omi mi omini
Tiise eru oje lepetu
Kere kere lekuja wo
Adifafun eera ti o seruko ako pole pe titi
Eera ti o se akapo ile petiti
Lodifafun ojugun to yo nuntan
To fi kun eyin gbendu
Ojugun toyonuntan to fikuneyingbendu
Lodifafun Orunmila
Nijo ajogun lan sedi nan ile baba re
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni todafa yi ko rubo ki ire ba le te lowo ifa ni oju ire gbogbo nipon eleyi ko sirubo fun omo re kan ko mo ba soun ifa ni omo kan nbe nib eyen toni agidi ki won o rubo fun ki agidi yen mon ba pa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Akuko
Eye etu
Opa aso funfun mefa
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Egbo tannaposo ao lo po mo iyere ao fi se eran elede ti a ge si merindinlogun (16) leponiyo ti o ba jinnaan ao se adua si ao ko je
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Egbo odun pupo egbo atori pupo odidi atare kana o jo po ao o ma fi fo eko tutu mu larolaro
Explore Ifa
Ogunda Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogunda Meji, Ogunda Ogbe, Ogunda Oyeku, Ogunda Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogunda Irosun Odu.
