O
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness in personal growth.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Aduropon aberepon
Adifafun jaja niwara
Ti se inanja oni
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o mon bo ori re dada ki o mon gbekele oogun nkan ki o si mon peese fun awon agbalagba dada kosi mon rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Akuko adie mejiEyelemeji
Okete
Ki ofi eye etu kan
Bo ori re pelu obi ati oti
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Kokole beeni kosun ori igi
Koroko koje erupe ile
Ko bawon gbongun oowe kotoro eja je lowo won
Kotoro okasa lowo gbondo gbondo
Adifafun aja olele
Tin sawo lo sode oroo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire lati ipase obinrin fun eleyi, Ifa eleyii si nwa obinrin korubo daada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbeboadie meji
Eye etu meji
akuko kan
Obi
Oti
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ogunda olapo
Iwori o lofa
Ofa kan soso ofa iwori
Tin be ninu apo ni n sapo yoroyoro
Adifafun aluba ile
Abufun aluba ode
Won n torun bowaye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii rubo ire gbogbo ki ire ole to lowo ki osi rubo nipase omo iyare kan ti yio laa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyelemeji
Akuko adie meji
Eyeetu meji
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ogunda fidi iwori joko
Adifafun Aje
Tii somo olusiki
Igba ti n torun bo waye
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori okete meta ewe mon fowo ba omo mi pupo odidi atare meta ao jo papo
Ao pe ifa si ao mon fi fo eko tutu mun lalelale
Explore Ifa
Ogunda Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include:Ogunda Meji,Ogunda Ogbe,Ogunda Oyeku,Ogunda Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogunda Iwori Odu.
