O
This Odu emphasizes the importance of strategic planning and thoughtful decision-making.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Arogbagede gba
Adifafun enlojo igi oko
Won n sunkun pawon o lolori
Adifafun afomo ti won o mun joba igi loko
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ki o rubo ni tori ogun ifani Ibi kan ni eleyi fe lo ki o rubo ifa ni o fe loda bo boa won kan nibi kan ko rubo kole ba se see fun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Eye Etu
Pepeye
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Orunmila wi odi si la sila
Ifa mo ni odi silo silo
Orunmila ni ki n lese sila sila si
Ki lese silo silo si
Omo eku ni tori omo ni
Omo eja ni tori omo ni
Omo eye ni tori omo ni
Omo eran ni tori omo ni
Omo eniyan naa nitori omo ni
Orunmila ni won o maa bi yaya
Won o mo bi yaayaa
Won o mo bi yanya
Baba omo won ni won o karagiri
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifa yi ki eleyi o rubo apesin ifa ni won nifi ojudi eleyi ifa ni yodi olopo eyan ifa ni awon kan tinro pin pe ko le ni lari ko rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Pepeye
Igbin
Opolopo owo
Aso funfun
Ori lopolopo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ogun polowo odo
Gbere ga san ponanpo ni gbowo
Adifafun eta
To lojo ale ti koni taro
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifa yi ko rubo ki ire ole bato lo wo ifa ni ko si oluranlowo fun ko sisi eni tole foro lo ifani gbogbo oun ti dun oun ifa ni ko mo so fun pe oun osi ba gbo gbogbore
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Eyele
Agbebo adie
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Koro koro miwa
Aja koro mi wa
Adifafun orunmila
Baba n be larin ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifa yi ifa ni awon kan ba eleyi se ota korubo ko le ba segun won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Agbebo adie
Eye Etu
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe wawa ewe saworopepe ewe ikanjije ede pupa ao gun papomo ose dudu ti aba gun tan a o toju oruko kan a o pa si ose a o po gbogbo. Eje oruko yi mo ose a o fi ori oruko yi tele igba funfun toni omori a o wa ko ose le a o fi omo rirede a o ma fiwe laro laro.
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe Abo a o ja ti yopo dada a o wa jo pomo odidi atare kan ti aba ti jo tan a o ro sinu a to a o ma fi epo pupa lo ninu awo amo.
Explore Ifa
Ogunda Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogunda Meji, Ogunda Ogbe, Ogunda Oyeku, Ogunda Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogunda Otura Odu.
