O
This Odu highlights the need for patience and perseverance in achieving success.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ogunda kete penpe
Adifafun orangun mojo
Ti o joye ti o ju babare
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Awon meji kan ni won jo n sota yii, sugbon keleyi orubo yio segun nitori ota eleyi to bi ju lo sugbon yio segun re keleyi o si bo ogun agbede obi ni yoo fi bogun agbede.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ogunlode popo iko
Lorawo agada ibeje ibeje
Adifafun ajayi
Ti won ni ko ni joye amodun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Obinrin eleyi ni keleyi o rubo fun ki won ota oman pa ni tori iyawo eleyi ni ota pupo ota ti moun wi yi lati idile obinrin naa ni won ti le wa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Agogonla abi enu gbaagba
Adifafun elewi
Ti n sogbogbo arun tin nirakaka alailedide
Kabojuju kaitele jujo
Omo elewii obojuju telejuju omo elewi ni
O bo bata tele fijuju le omo
Elewii ehoro omo elewi ni
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ibikan lawon eleyi n lo, ki won o orubo, ki won o to lo won yoo la bo ibe, won o fi opolopo agbado kun ebo won ru, ki won osi man jara won niyan, ki ire won oman ba fo won ru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Eyele kan
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Kenu momonu
Kete momo ete
Ni koran beke
Adifafun ehoro tii se wole wode orisa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo, ko si se aase onje oti fun awon awo kire aje eleyi ole to lowo, odo eeyan nla kan leleyi n lo yii, yio rire munbo, eni nan tin damu lori ikan re kan, sugbon eleyi ni yio ba soro re dayo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fi opolopo onje obi oti bo ifa
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Egun igbago opolopo isu eminan ikoode kan odidi atare kana o jo po ao man fi epo pupa la lale sun
Explore Ifa
Ogunda Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogunda Meji, Ogunda Ogbe, Ogunda Oyeku, Ogunda Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogunda Irete Odu.
