O
This Odu emphasizes the importance of transformation and embracing new beginnings.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ogunda Yeku
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ogunda o ku
Oye oku
Aiku loloja ntora
AdifafunorunmilaBaba o ranmo meji lajo
Baba ji ni jojumo oun komi nu won
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni toda ifayi to ba jepe o felo si irin ajo korubo ko to lo to ba sije pe o feran yan lo ni ko rubo fun eninaa ko to lo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo owoeyele
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Lodun lodun ni won ko ile kin
Losun losun ni won yo odede imo
Kirimun kirimun
Adifafunonilekere ope ogunka mo si yele
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ko rubo kosi mo se iya meji lodo ifa ni oore re wa
Ifa pere fun eni to da ifayi korubo ki ire ole bato lowo ifa ni toba je pe eleyi ferin irinajo kan lo fi wa dafa ko rubo kin opun tin balo kole ba yori sirere kobo ifa koto lo
Ifa pere fun eni toda ifa yii ifa ni korubo ifa ni obinrin kan lele yi fefe korubo ko ba lo rife ifa I to ba fa tan alalubari kani obinrin ifa gbogbo oun toba ni ko se ni obinrin naa yose.
Ifa pere fun eni toda ifa yi ko rubo kilere ole badero ko fi opolopo igbin kun EBOru ifa ni eleyi ti gbin yanju titi korubo ki ara o le baro
Ifa pere fun eni to da ifayi ko rubo ni tori aje ifa pe oju aje nipon eleyi ko fi emun bogun ni tori aje.
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ogunda oku
Oye o ku
Aiku lagba lagba meji fin ra won
Adifafun oke eyi to soko aiku
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni to da ifa yi ko rubo ifa pe oun pere laiku fun ki oun ati iyawo re ki won o jo rubo ifa pe oun o se aikuwon
Ifa pere fun eni toda ifa yi ki eleyi orubo isegun ifa ni arin ota ni eleyi wa ifa pe oun loun ogba kale togun o fi ni mun
Ifa pere fun eni toda ifayi korubo ifa ni ire isegun moun rifun eleyi ifa pe oun pere aikun
Ifa pere fun eni toda ifayi korubo ifa ni to baje pe obinrin kan ti fi sile ifani oun padabo ibi tolo ko ni rolorun.
Ifa pere fun eni to da ifayi ifani ki eleyi komo juba baba ati iyare orire ati orunoba ko si bo gbogbo irunmole ni obi ki oro ole ba loju yo fi agbo bo baba re.
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ma sere maku
Masika maku
Ile lomo eni to te oun pe
Adifafun aikulola tii se iponti orisa
Igba ti n momi oju so gbere ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni toda ifa yi ki eleyi o rubo ki ire o le ba to lowo ifa ni oju aje nipon eleyi ifa ni oun fore AJE fun oun si fore aya oun fore omo oun si fore gbogbo fun ko fi oliboorisanlaIfa pere fun eni toda fayi ifani oju AJE pon eleyi pe ko rubo ifa si ni oju ire gbogbo ni pon eleyi ifa pe ire gbogbo loun fo fun eleyi ko rubo ki ire naa o ba tete de ifa ni ko ruba akojo
Ifa pere fun eni toda ifayi ko rubo fun akobire nitoriogunifa pe oun o ba eleyii segun
Ifa pere fun eni to da ifayi ko si rubo si enu ise re ifa ni eleyii n sowo ko jere awon araile re won si fi se yeye korubo
Ifa pere fun eni toda ifa yi pe ki eleyi o rubo intori ajogun ki orubo nitori ko fi ewure bo fa ko fi okun re won orire leme ta.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ewe areyinkosun obi idi esu owo eyo ti ko luju meta ao gun pomo ose ao ko sinu paka idi esu ao ma fiwe laro laro
Opolo aye kan igbomimun die owo tutu murimarun (N100 ao ko igbo sinu owo yi ao ra rEBOrobo bi siga ao kibo enu opolopo yi ao wa jo pa pelu odidi atare kan ao ro sinu sere ao pa ejeeyelefunfun meta si ara sere yi ao nije ninueyeleyi o ao fi pa ese fun awon iya mi ni o ao bere ibi ti won ba ti gba ao gbe lo fun won ao ma fi oti lo ebu yi laro laro
Ewe obibo sere yo pipo ao jopo mo odidi atare ao fi sin gbere yipo orun owo mejeeji
Ewe AJE ede pupa ao lo po mo iyere ao fi se eyele meji igbin meji eyinadie meji lepo niyo ti o bajina ao koje
Ewe akoko ao lopo mo iyere ao fi se igbin merindinlogun (16() leponiyo tio ba ti jinanm ao wa je
Ewe akisan iru woro eru Alamo ewe omo nigbedegede yanrin oku yanrin osa ao gun pomo ose ao ma fiwe larolaro pelo ofo yi
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Egbo iya lode (lapalapa) ao gun po mo ose ao ma fiwe lale katosun tiaba ti fiwe tan ao nijademo o odi aro ojo keji ka tojade
Opa tiwon fis in eku ati apa ti won fi sin eja iya ti won fi di obi ewe alupaida meta ao lo papo ao fi sin gbere yipo orun wa
Ata pupa meje ewe alupaida meje ao lo pomo arawon ao fi singbereogunole eyo si arin ori
Orogbo meji atare meji obi ajopa meji aojopomo odidi atare kan ao fi sin gbereogunatieyo si arin ori
Explore Ifa
Ogunda Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ogunda Yeku. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include:Ogunda Meji,Ogunda Ogbe,Ogunda Iwori,Ogunda Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogunda Oyeku Odu.
